NIHIN l’ awa nje ‘rora
NIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to!
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘rora643 hymns
NIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to!
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘roraNIHIN l’ ayida wa, Ojo, erun nkoja; Ile ni nyan, ti o si nsa, ‘Tana dada si nku;
Read hymn : NIHIN l’ ayida waNIHIN l’ Olorun sin mi de, De ‘hin n’ ipa Re sun ‘jo mi, Gbogbo asale yio si fi Ami ore Re titun han.
Read hymn : NIHIN l’ Olorun sin mi deNIHIN mo j’ alejo, Orun n’ ile. Aginju l’ aiye yi, Orun n’ ile.
Read hymn : NIHIN mo j’ alejoNIHIN, l’ oko Re Oluwa, A ko ‘le ‘rupe yi fun O, Yan fun ‘bugbe Re Pataki, K’ O si so lowo asise.
Read hymn : NIHIN, l’ oko Re OluwaNIHINYI n’ isimi gbe wa, N’iha Re t’ eje nsan; Eyi nikan n’ ireti mi, Pe Jesu ku fun mi.
Read hymn : NIHINYI n’ isimi gbe waNINU gbogbo ewu oru, Oluwa l’ O nso wa; A wa tun ri imole yi, A tun tee kun ba.
Read hymn : NINU gbogbo ewu oruNINU gbogbo iji ti nja, Ninu gbogbo igbi ‘ponju, Abo kan mbe ti o daju, O wa labe ite-anu
Read hymn : NINU gbogbo iji ti njaNINU oru ibanuje, L’ awon egbe ero ayo, Nwon nkorin ‘reti at’ ayo, Nwon nlo s’ ile ileri.
Read hymn : NINU oru ibanujeNIPA ife Olugbala, Ki y’o si nkan; Oju rere Re ki pada. Ki y’o si nkan.
Read hymn : NIPA ife OlugbalaNIWAJU ite anu Re, Jesu, a tun ko ‘ra wa de, A wa toro idariji, Fun majemu t’ a ti baje.
Read hymn : NIWAJU ite anu ReNIWAJU ‘te Jehofa nla, Oril’-ede e f’ ayo sin; Mo p’ On nikan ni Olorun, O le da, Osi le parun.
Read hymn : NIWAJU ‘te Jehofa nlaNJ’ Onidajo yio wa? Nj’ oku yio ji dide? Nje ko s’ eniti yio le sa Kuro ni oju Re?
Read hymn : NJ’ Onidajo yio waNKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘le, Ko tun si ona miran; Nko le ri ilekun imole na Bi nko si l’ ona agbelebu.
Read hymn : NKO le sai gb’ ona agbelebu lo ‘leNWON duro fun ete kan Nwon gbo t’Olorun; Bola fun Olotito K’a nyin egbe Daniel –
Read hymn : NWON duro fun ete kanN’IFE l’ a te ona T’ Olugbala ti rin; A f’ apere Olori wa, Agutan Olorun.
Read hymn : N’IFE l’ a te onaN’NU ‘se, n’nu ‘ja, Oluwa mi, Ngo rin li ona Re; B’ Iwo ti se l’ emi o se, Nipa iranwo Re.
Read hymn : N’NU ‘se, n’nu ‘ja, Oluwa miO FUN mi l’ edidi, ‘Gbese nla ti mo je; B’ O ti fun mi, O si rerin Pe, “Mase gbegbe Mi!”
Read hymn : O FUN mi l’ edidiO HA le je p’ a mi? Olugbala ha yan mi? Bi ebi mi tip o to O ha da oruko mi?
Read hymn : O HA le je p’ a mi“O SUN,” ni Jesu wi Nipa ti Lasaru, Enit’ o ku, ti a ti san, T’ a ti te s’ iboji.
Read hymn : O SUN,” ni Jesu wiO TI to Jesu f’ agbara ‘wenumo? A we o nin’ ej Odagutan? Iwo ha ngbekele ore-ofe Re? A we o nin’ ej Odagutan?
Read hymn : O TI to Jesu f’ agbara ‘wenumoOBIRIN t’ a mu ninu pansaga ‘se On la mu wa fi sun niwaju Jesu; Jesu terire ba. O nkowe n’ ile; T’ agba t’ ewe nf’ obirin yi seleya.
Read hymn : OBIRIN t’ a mu ninu pansaga ‘seODE, Kristi Oluwa, Lat’ ibugbe Re l’ orun, Lat’ ite alafia. O wa si aginju wa.
Read hymn : ODE, Kristi OluwaODODO Re nikan laise t’ emi, L’ o le se isimi fun okan mi; Ife Re l’ o le mu k’ ifoiya lo, L’ o le da iji okan mi l’ ekun.
Read hymn : ODODO Re nikan laise t’ emi