B’ AWON ara igbani
B’ AWON ara igbani Ti f’ ayo ri ‘rawo na; Bi nwon ti f’ inu didun Tele ‘mole didan re;
Read hymn : B’ AWON ara igbaniB’ AWON ara igbani Ti f’ ayo ri ‘rawo na; Bi nwon ti f’ inu didun Tele ‘mole didan re;
Read hymn : B’ AWON ara igbaniTIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re, O nso ife Re si mi: Sugbon mo fen de l’ apa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O.
Read hymn : TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun ReTIRE lailai l’ awa se, Baba Olorun ife; Je k’ a je Tire titi, L’ aiye yi, ati lailai.
Read hymn : TIRE lailai l’ awa seISUN kan wa t’o kun f’eje O yo n’iha jesu, Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi.
Read hymn : ISUN kan wa t’o kun f’ejeDIDE okan mi, nde Gbon eru ebi nu; Ebo eje t’a ru Nitori mi yoju:
Read hymn : DIDE okan mi, ndeJESU ti mo gbeke mi le, At’ ireti mi lo s’ orun: Mo r’ ipa Re, ngo si tele Ona Re titi ngo fi ri.
Read hymn : JESU ti mo gbeke mi leAPATA aiyeraiye, Se ibi isadi mi! Je ki omi on eje T’ o san lati iha Re
Read hymn : APATA aiyeraiyeNIGBA itiju k obo mi, Mo f’ eru sa b’ agbelebu; Pelu eru ebi lori, Ife fa mi, mo bo ‘waju,
Read hymn : NIGBA itiju k obo miJESU oluf’ okan mi, Je ki nsala s’ aiya Re; Sa t’ irumi sunmo mi, Sa ti iji fe s’ oke;
Read hymn : JESU oluf’ okan miJESU, ise Re l’o Fi ayo s’okan mi, Nwon ni, o ti pari, Ki eru mi ko tan:
Read hymn : JESU, ise Re l’oBI mo egbarun ebun, Ngo di mo Jesu ti a pa, Y’o je ipile mi; ‘Tori ko s’ ipile miran,
Read hymn : BI mo egbarun ebunKo s’ ona si ayo orun, S’ ayo at’ alafia toto, Lehin Jesu, Ona; Jek’ a rin l’ ona mimo na,
Read hymn : Ko s’ ona si ayo orun