ILE ayo kan wa
ILE ayo kan wa Ti o Jina, Ti awon mimo wa; Nwon nran b’ orun;
Read hymn : ILE ayo kan wa643 hymns
ILE ayo kan wa Ti o Jina, Ti awon mimo wa; Nwon nran b’ orun;
Read hymn : ILE ayo kan waILE ewa wonni, b’ o ti dara to! Ibugbe Olorun, t’ oju ko ti ri; Tal’ o fe ibe, lehin aiye yi? Tal’ o fe k’ a wo on ni aso funfun?
Read hymn : ILE ewa wonni, b’ o ti dara toILE ‘simi, mo nreti re, ‘Gbawo n’ igba yio de, Ti ngo bo ‘hamora sile, Ti ngo wa pelu Krist”?
Read hymn : ILE ‘simi, mo nreti reILE-EKO ojo ‘sinmi, A, mo ti fe O to! Inu mi dun mo daraya Lati yo ayo re
Read hymn : ILE-EKO ojo ‘sinmiILU mi, orin re, Ilu mi omnira Li emi nko; Il’ awon baba mi,
Read hymn : ILU mi, orin reILU t’ o dara po l’ aiye; Betlehem’, ‘wo ta won yo; Ninu re l’ Oluwa ti wa Lati j’ oba Israel’.
Read hymn : ILU t’ o dara po l’ aiyeIMOLE k’ okan mi loni, T’ o logo t’ o si ndan, T’ o tan ju t’ awosanma lo, Jesu n’ imole mi.
Read hymn : IMOLE k’ okan mi loniIMOLE ojo ‘simi Je l’ o ku mo wa l’ oju, B’ igbat’ orun iba wo, Fun ajo onigbagbo.
Read hymn : IMOLE ojo ‘simiIRANSE Oluwa! E duro nid’ ise; E toju oro Re mimo, E ma sona Re sa,
Read hymn : IRANSE OluwaIRANSE, e fonrere Oba nyin, E si tan ‘hin oruko nla Re ka, Gbe oruko Asegun ti Jesu ga, Ijoba Re l’ ogo, o ka gbogb’ aiye.
Read hymn : IRANSE, e fonrere Oba nyinIRE t’ a su ni Eden’, N’ igbeyawo ‘kini, Ibukun t’ a bukun won O wa sibesibe.
Read hymn : IRE t’ a su ni EdenIRO t’ o dun ju orin, Fa mi l’ oruko Jesu, Gbogbo ‘reti okan mi Wa lor’ agbelebu Re.
Read hymn : IRO t’ o dun ju orin