IMOLE ojo ‘simi
IMOLE ojo ‘simi Je l’ o ku mo wa l’ oju, B’ igbat’ orun iba wo, Fun ajo onigbagbo.
Read hymn : IMOLE ojo ‘simiIMOLE ojo ‘simi Je l’ o ku mo wa l’ oju, B’ igbat’ orun iba wo, Fun ajo onigbagbo.
Read hymn : IMOLE ojo ‘simiIRANSE, e fonrere Oba nyin, E si tan ‘hin oruko nla Re ka, Gbe oruko Asegun ti Jesu ga, Ijoba Re l’ ogo, o ka gbogb’ aiye.
Read hymn : IRANSE, e fonrere Oba nyinIRANSE Oluwa! E duro nid’ ise; E toju oro Re mimo, E ma sona Re sa,
Read hymn : IRANSE OluwaIRE t’ a su ni Eden’, N’ igbeyawo ‘kini, Ibukun t’ a bukun won O wa sibesibe.
Read hymn : IRE t’ a su ni EdenIRO t’ o dun ju orin, Fa mi l’ oruko Jesu, Gbogbo ‘reti okan mi Wa lor’ agbelebu Re.
Read hymn : IRO t’ o dun ju orinISE re Oluwa, Awamaridi ni, Ohun gbogbo ni mu ‘re wa, F’ eni to se ‘fe Re.
Read hymn : ISE re OluwaISE ‘gbala pari, Jesu ti ba ‘ku ja, O se agbara iboji, O ti di asegun.
Read hymn : ISE ‘gbala pariISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yi, Emi o se kun, ‘gbat’ iyonu ba de; Simi okan mi, eyikeyi t’ o de, O dun ajo mi ku, o mu k’ ile ya.
Read hymn : ISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yiISIN l’ o le fun wa li Ayo didun li aiye; Isin ni yio fun wa li Itunu nigba ba ku.
Read hymn : ISIN l’ o le fun wa liISUN kan wa t’o kun f’eje O yo n’iha jesu, Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi.
Read hymn : ISUN kan wa t’o kun f’ejeITANA t’ o bo ‘gbe l’ aso, T’o tutu yoyo be; Gba doje ba kan, a si ku, A subu, a siro.
Read hymn : ITANA t’ o bo ‘gbe l’ asoITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan si, Itan iyanu t’ ife! Ti dun l’eti kikan! Awon Angeli rohin re, awon oluso si gbagbo Elese iwo ki yio gbo? Itan iyanu t’ife.
Read hymn : ITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan si