GBAT, a b’Oluwa rin
GBAT, a b’Oluwa rin N’nu ‘mole oro Re Ona wa yi o ti l’ogo to! ‘Gbat’ a ba nse f’e Re
Read hymn : GBAT, a b’Oluwa rinGBAT, a b’Oluwa rin N’nu ‘mole oro Re Ona wa yi o ti l’ogo to! ‘Gbat’ a ba nse f’e Re
Read hymn : GBAT, a b’Oluwa rinAYO omo anu ti to! T’ o mo idariji: O nwip’ aiye ki se ‘le mi, Mo nwa ‘le mi s’ orun
Read hymn : AYO omo anu ti toAYO awon ti to, T’ o gb’ Olugbala gbo, T’o to isura nwon si oke Ahon ko le s’ adun
Read hymn : AYO awon ti toBENI, O bikita fun mi, Pelu ike bi t’ egbon ; Beni, eru at’ ifoiya, Gbogbo re l’ O mba mi pin.
Read hymn : BENI, O bikita fun miJESU o ye ki nl’ ayo, Ti mba le gbekele O, Pe ogbon Re to to mi, Pe ore Re to pese,
Read hymn : JESU o ye ki nl’ ayoBI Jesu ba fe mi, Bi mo ba je Tire, Nko ko ohun t’ ota le ro, Bi nwon tile n’ ipa.
Read hymn : BI Jesu ba fe mi.ALAFIA pel’ Oluwa, A, ede wo l’ eyi! A f’ eje b’ elese la ‘ja, Oto ‘simi l’ eyi.
Read hymn : ALAFIA pel’ OluwaOKAN mi nsimi, Oluwa; Ngo dupe, ngo ko ‘rin, Okan mi r’ ibi asiri Ti ire ti nsun wa.
Read hymn : OKAN mi nsimi, OluwaENYIN t’ e fe Oluwa, E fi ayo nyin han, E jumo ko orin didun, E jumo ko orin didun,
Read hymn : ENYIN t’ e fe OluwaMO gbohun Jesu t’ o wipe, “Wa simi lodo Mi; Gbe ori re, ‘wo alare, Le okan aiya Mi.”
Read hymn : MO gbohun Jesu t’ o wipeISIN l’ o le fun wa li Ayo didun li aiye; Isin ni yio fun wa li Itunu nigba ba ku.
Read hymn : ISIN l’ o le fun wa liJESU, kiki ironu Re, Fi ayo kun okan; Sugbon k’ a ri O l’ o dun ju, K’ a simi lodo Re.
Read hymn : JESU, kiki ironu Re