MA so fun mi l’ ohun aro
MA so fun mi l’ ohun aro Pe iye dabi ala; Okan ti ntogbe li o ku, ‘Kan ko ri bi a ti nro.
Read hymn : MA so fun mi l’ ohun aroMA so fun mi l’ ohun aro Pe iye dabi ala; Okan ti ntogbe li o ku, ‘Kan ko ri bi a ti nro.
Read hymn : MA so fun mi l’ ohun aroYIKA or’ ite Olorun, Egberun ewe wa; Ewe t’ a dari ese ji, Awon egbe mimo,
Read hymn : YIKA or’ ite OlorunORE kan mbe fun omode Ninu awon orun; Ore ti ki yipada, T’ ife Re ko le ku;
Read hymn : ORE kan mbe fun omodeNIGBAKAN ni Betlehemu Ile kekere kan wa; Nib’ iya kan te ‘mo re si Lori ibuje eran;
Read hymn : NIGBAKAN ni BetlehemuSA dake, okan mi, Oluwa re wa n’be, Enit’ o ti se ileri, Yio fe mu u se.
Read hymn : SA dake, okan miKINI gbogbo lala Re L’ ori mi fun, Jesu, At’ anfani t’ O fun mi Ju awon miran lo?
Read hymn : KINI gbogbo lala ReTAL’ o mo adun isimi, B’ o ye l’ awon t’ o ni, Ti se ‘pin awon ayanfe, Nipa eje Jesu?
Read hymn : TAL’ o mo adun isimiJESU, nigba aiye Re, O ko dekun wo arun; Igbe irora aisan Ko kan O k’ o bo ‘le ri.
Read hymn : JESU, nigba aiye ReOLUSAGUTAN ni npe mi, Kuro nin aginju ese, On p’ agutan t’ o sako lo Jina rere sinu agbo.
Read hymn : OLUSAGUTAN ni npe miB’ IFE Olugbala ti dun to! Bi t’ okun iwon re tayo; Ewa didara re julo ni Pe o to tile ndun si ni fun mi,
Read hymn : B’ IFE Olugbala ti dun toESE t’ onigbagbo mberu? Kini ‘ba ma da won l’ amu? Iku Jesu le ‘foya lo, O mu isimi sokale.
Read hymn : ESE t’ onigbagbo mberuOM’ Olorun, a ko ri O, ‘Gbat’ O wa s’ aiye iku yi; Awa ko ibugbe Re, Ni Nasareti ti a gan;
Read hymn : OM’ Olorun, a ko ri OIGBAGBO l’ ategun t’ o so Orun at’ aiye po; On l’ Olugbala fi sise Iyanu Re l’ aiye.
Read hymn : IGBAGBO l’ ategun t’ o soOLORI ijo t’ orun, L’ ayo l’ a wole fun O; K’ o to de, ijo t’ aiye, Y’o ma korin bi t’ orun,
Read hymn : OLORI ijo t’ orunOLORUN fe araiye, O fe tobe ge, T’ O ran Omo Re w’ aiye T’ O ku fun elses;
Read hymn : OLORUN fe araiyeNIHIN l’ Olorun sin mi de, De ‘hin n’ ipa Re sun ‘jo mi, Gbogbo asale yio si fi Ami ore Re titun han.
Read hymn : NIHIN l’ Olorun sin mi deLARIN ewu at’ osi, Kristian, ma te siwaju, Roju duro, jija na, K’ onje ‘ye mu o l’ okun.
Read hymn : LARIN ewu at’ osi.EREDI iwa s’ aiye mi? ‘Tori kil’ a bi mi? Gbogb’ ohun l’ aiye l’ o n’ idi, Kil’ a ha da mi fun?
Read hymn : EREDI iwa s’ aiye miJEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re;
Read hymn : JEJE, lai si ariwoOLUWA, iji nfe s’ oke! Igbi omi nru s’ oke! Oju orun pelu su dudu, ‘Ranlowo ko si n’ tosi;
Read hymn : OLUWA, iji nfe s’ okeOJO ibukun yio sir o!” Eyi n’ ileri ife; A o ni itura didun Lat’ odo Olugbala
Read hymn : OJO ibukun yio sir oGBA Jesu ba de lati pin ere, B’ o j’ osan tabi l’ oru, Y’o ha ri wa nibit’ a gbe ns’ ona, Pel’ atupa wa tin tan?
Read hymn : GBA Jesu ba de lati pin ereLAB’ agbelebu Jesu Mo fe lati duro, – Oji apata titobi Ninu ile are,
Read hymn : LAB’ agbelebu JesuFUN mi n’ iwa pele, Okan tutu; Ifarabale bi T’ Oluwa mi;
Read hymn : FUN mi n’ iwa pele