JESU awa nwo O fun
JESU awa nwo O fun ‘Wosan alailera yi ‘Wo lo ti se anu nla, F’ abiirun let’ adagun.
Read hymn : JESU awa nwo O funJESU awa nwo O fun ‘Wosan alailera yi ‘Wo lo ti se anu nla, F’ abiirun let’ adagun.
Read hymn : JESU awa nwo O funJESU a w’ odo Re L’ ojo Re mimo yi; To wa wa ba wa ti pejo, Si ko wa fun ‘ra Re.
Read hymn : JESU a w’ odo ReJESU bukun oro Re, K’ o le tete f’ ipa han; Ki elese gbo ‘pe Re, K’ enia Re dagba n’nu ‘fe.
Read hymn : JESU bukun oro ReJESU b’ oluso, ma sin wa, A nfe, ki Re pupo; F’ onje didara Re bow a, Tun agbo Re se fun wa;
Read hymn : JESU b’ oluso, ma sin waJESU fe k’ emi je ‘mole, Ki ntan lojojumo; Nibi gbogbo kin le wu On, N’ ile, ni skul, l’ode.
Read hymn : JESU fe k’ emi je ‘moleJESU fe mi, emi mo; Bibeli so fun mi be; Tire l’ awon omode, Nwon ko l’ agbara, On ni.
Read hymn : JESU fe mi, emi moJESU f’ ara han nitoto, Nibi ase ‘yawo; Oluwa, awa be O, wa F’ ara re han nihin.
Read hymn : JESU f’ ara han nitotoJESU f’ eje Re raw a, E jek’ a sunm’ Olorun; Opo nsina yi wa ka; K’ anu mu wag badura, –
Read hymn : JESU f’ eje Re raw aJESU l’ Olusagutan mi, Ore Eniti ki ye! Ko s’ ewu bi mo je Tire, T’ On sije t’ emi titi.
Read hymn : JESU l’ Olusagutan miJESU ma to wa Tit’ ao fi simi; Bi ona wa ko tile dan, A o tele O l’ aifoya;
Read hymn : JESU ma to waJESU mo bg’ agbelebu mi, Ki nle ma to O lehin; Otosi at’ eni egan, ‘Wo l’ ohun gbogbo fun mi;
Read hymn : JESU mo bg’ agbelebu miJESU nfe gba elese,, Kede re fun gbogb’ eda; T’o yapa ona ‘run ‘le, At’ awon ti njafara.
Read hymn : JESU nfe gba elese