JESU Oba, a pari eko wa
JESU Oba, a pari eko wa, Ma jeki Esu sa je l’ okan wa.
Read hymn : JESU Oba, a pari eko wa643 hymns
JESU Oba, a pari eko wa, Ma jeki Esu sa je l’ okan wa.
Read hymn : JESU Oba, a pari eko waJESU Od’-agutan, ‘Wo t’ O ta ‘je Re le, Lati gba wa lowo ‘parun, Gba iyin ailopin.
Read hymn : JESU Od’-agutanJESU oluf’ okan mi, Je ki nsala s’ aiya Re; Sa t’ irumi sunmo mi, Sa ti iji fe s’ oke;
Read hymn : JESU oluf’ okan miJESU Oluwa mbo, Lati se ‘dajo wa, Yio san f’ olukuluku, Gege bi ise re.
Read hymn : JESU Oluwa mboJESU Onirele, Omo Olorun: Alanu, Olufe, Gbo ‘gbe omode.
Read hymn : JESU OnireleJESU Or’ elese mo de, Em’ otosi wa fun ‘rawo, Ara mi su mi fun ese, Na apa Re gba mi s’ ile.
Read hymn : JESU Or’ elese mo deJESU pe omode, O gbe won s’ aiya Re; O f’ owo Re gba won mora, O si sure fun won.
Read hymn : JESU pe omodeJESU ti mo gbeke mi le, At’ ireti mi lo s’ orun: Mo r’ ipa Re, ngo si tele Ona Re titi ngo fi ri.
Read hymn : JESU ti mo gbeke mi leJESU t’ asia Re bow a, O f’ onje m’ okan way o; O te ase siwaju wa, T’ a f’ eran ara Re se.
Read hymn : JESU t’ asia Re bow aJESU t’ O wa gba mi la, Wo ‘nu odo Jordani, O jade kuro n’nu re, A si m’ O l’ Om’-Olorun,
Read hymn : JESU t’ O wa gba mi laJESU t’o k’o gb’aiye la, Jinde kuro ninu oku, Nipa agbara Re; A da, sile lowo iku,
Read hymn : JESU t’o k’o gb’aiye laJESU wipe k’ a ma sora Ni wakati gbogbo, O si nf’ emi isoji fun Awon t’ o mbere re.
Read hymn : JESU wipe k’ a ma sora