OKAN mi yin Oba orun
OKAN mi yin Oba orun, Mu ore wa sodo Re; ‘Wo t’ a wo san, t’ a dariji, Tal’ a ba ha yin bi Re?
Read hymn : OKAN mi yin Oba orunOKAN mi yin Oba orun, Mu ore wa sodo Re; ‘Wo t’ a wo san, t’ a dariji, Tal’ a ba ha yin bi Re?
Read hymn : OKAN mi yin Oba orunYIN Olorun Abra’am, T’ o gunwa lok’ orun, Eni agba aiyeraiye, Olorun ife;
Read hymn : YIN Olorun Abra’amFUN aanu t’ o po b’ iyanrin, Ti mo ngba lojojo Lat’ odo Jesu Oluwa, Kili emi le tun?
Read hymn : FUN aanu t’ o po b’ iyanrinITE anu! E je k’a lo Lati gba adura; Olorun ‘fe y’o sanu fun Awon t’o nsin nibe.
Read hymn : ITE anu! E je k’a loNINU gbogbo iji ti nja, Ninu gbogbo igbi ‘ponju, Abo kan mbe ti o daju, O wa labe ite-anu
Read hymn : NINU gbogbo iji ti njaIKOSE ti po to, t’ a nri Li ona wa s’ ite anu Sibe, tani mo ‘yi adua Ti ki y’o fe ma wa nibe.
Read hymn : IKOSE ti po to, t’ a nriLODO Re sibe nigbat’ ojumo mo, Ti awon eiye ji, ti kuku lo: Rekoja t’ orun ni didan imole, Idaloju pe, “O wa lodo mi.”
Read hymn : LODO Re sibe nigbat’ ojumo moJE, Oluwa, sin wa jeje, L’ aiye omije yi ja, Si fun wa l’ ore-ofe Re Ninu eru wa gbogbo:
Read hymn : JE, Oluwa, sin wa jejeNGO sunm’ O, Olorun, Ngo sunmo O; B’ o tile se ‘ponju, L’ o mu mi wa;
Read hymn : NGO sunm’ O, OlorunOLORUN lat’ oro d’ ale, Wakati wo l’ o dun pupo, B’ eyi t’ o pe mi wa ‘do Re Fun adua?
Read hymn : OLORUN lat’ oro d’ aleWA k’ a da m’ awon ore wa Ti nwon ti jere na; N’ ife k’ a f’ okan ba won lo S’ ode orun lohun.
Read hymn : WA k’ a da m’ awon ore waGBA alare nwa sinmi, Ti nwon w’odo Re; Gba nwon ko ‘banuje won Wa si ‘waju Re;
Read hymn : GBA alare nwa sinmi