JESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tan
JESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tan, Bi fitila kekere ninu oru; L’ aiye okunkun yi, ka si tan, N’ ipo t’ iwo wa, at’ emi pelu.
Read hymn : JESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tanJESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tan, Bi fitila kekere ninu oru; L’ aiye okunkun yi, ka si tan, N’ ipo t’ iwo wa, at’ emi pelu.
Read hymn : JESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tanJESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘le O npe loni, o npe loni! Ese t’ o fi ko ife Re sile, T’ o sako jinna rere?
Read hymn : JESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘leJESU ni, “Gb’ agbelebu re Ki o si ma tele Mi,” Oro yi ha le mu wag bon? A o ha sa fun eru na?
Read hymn : JESU ni, “Gb’ agbelebu reJESU nigba ‘danwo, Gbadua fun mi; K’ emi ma ba se O, Ki nsi sako lo:
Read hymn : JESU nigba ‘danwoJESU ni gbogb’ aiye fun mi, Iye at’ ayo mi, Agbara mi lojojumo, L’ aisi Re mo subu;
Read hymn : JESU ni gbogb’ aiye fun miJESU npe wa l’ osan, l’ oru Larin irumi aiye; Lojojumo l’ a ngb’ ohun Re Wipe, “Kristian, tele Mi.”
Read hymn : JESU npe wa l’ osan, l’ oruJESU np’ enia Re S’ ori tabili Re, Nibi l’ awon t’ a dariji Nb’ Oluwa won dapo.
Read hymn : JESU np’ enia ReJESU Oba, a pari eko wa, Ma jeki Esu sa je l’ okan wa.
Read hymn : JESU Oba, a pari eko waJESU Od’-agutan, ‘Wo t’ O ta ‘je Re le, Lati gba wa lowo ‘parun, Gba iyin ailopin.
Read hymn : JESU Od’-agutanJESU oluf’ okan mi, Je ki nsala s’ aiya Re; Sa t’ irumi sunmo mi, Sa ti iji fe s’ oke;
Read hymn : JESU oluf’ okan miJESU Oluwa mbo, Lati se ‘dajo wa, Yio san f’ olukuluku, Gege bi ise re.
Read hymn : JESU Oluwa mboJESU Onirele, Omo Olorun: Alanu, Olufe, Gbo ‘gbe omode.
Read hymn : JESU Onirele