TORI Mi at’ ihinrere
TORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo;
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrere643 hymns
TORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo;
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrereT’ IFE Jesu t’o wa mi, Gbat’ mo nu n’ ese; T’ ore ofe t’ o mu mi Pada bo sin’ agbo;
Read hymn : T’ IFE Jesu t’o wa miT’ OLORUN n’ ijoba gbogbo Oril-ede, e korin ‘yin: E so t’ ipa Re to tobi; Ola Re y’o m’ orin yin dun.
Read hymn : T’ OLORUN n’ ijoba gbogboWA ba mi gbe! ale fere le tan, Okunkun nsu; Oluwa ba mi gbe, Bi oluranlowo miran ba ye, Iranwo alaini, wa ba mi gbe.
Read hymn : WA ba mi gbe! ale fere le tanWA Emi Mimo, wa, Pelu ipa t’ orun, Si ran ninu anu Re nla Sor’ okan okun wa.
Read hymn : WA Emi Mimo, waWA enyin oloto L’ ayo at’ isegun Wa kalo, wa kalo si Betlehem; Wa kalo wo o!
Read hymn : WA enyin olotoWA k’ a da m’ awon ore wa Ti nwon ti jere na; N’ ife k’ a f’ okan ba won lo S’ ode orun lohun.
Read hymn : WA k’ a da m’ awon ore waWA rohin Re yika K’o si korin ogo; Alagbara ni Oluwa Oba gbogbo aiye.
Read hymn : WA rohin Re yikaWA sodo Jesu, mase duro, N’ oro Re l’ O ti f’ ona han wa, O duro li arin wa loni, O nwi jeje pe, “Wa.”
Read hymn : WA sodo Jesu, mase duro“WA sodo Mi, alare Ngo fun nyin n’ isimi.” A! ohun didun Jesu, Ti o p’ elese wa,
Read hymn : WA sodo Mi, alareWA ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu nisin! Nisin wa’ do Jesu!
Read hymn : WA ‘do Jesu!WA, Emi ‘re, ‘Dada orun Pelu itunu lat’ oke; S’ alabo at’ Oluto wa, To ero at’ isise wa.
Read hymn : WA, Emi ‘re, ‘Dada orunWA, enyin olope, wa, Gbe orin ikore ga; Ire gbogbo ti wole K’ otutu oye to de;
Read hymn : WA, enyin olope, waWA, iwo isun ibukun, Je ki nkorin ore Re: Odo anu ti nsan titi, Bere orin ‘yin kikan;
Read hymn : WA, iwo isun ibukunWA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de.
Read hymn : WA, jek’ a tun pilese ajo waWA, Jesu fi ara han; Wa, je k’okan wa mo O: Wa, mu gbogb’ okan gbona, Wa, bukun wa k’a to lo.
Read hymn : WA, Jesu fi ara hanWA, ma sise, Tani gbodo s’ole ninu oko, Gbati gbogbo enia nkore jo? Kaluku ni Baba pase fun pe, –
Read hymn : WA, ma siseWA, obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist, ‘Mole Olorun,
Read hymn : WA, obirin, e koWA, Oluwa, l’ anu tun wa, Pelu ‘pa ‘p’ okan da, Ongbe ojo np’ oko Sion, Masai ro s’ ori re.
Read hymn : WA, Oluwa, l’ anu tun waWALEJO kan lenu ona: O nkankun je, O ti nkan ri; O ti duro pe, O nduro; Ko s’ ore t’ o je ba lo be.
Read hymn : WALEJO kan lenu onaWO b’ ikore tip o L’ otun l’ osi wa, Alagbase kere L’ ogba Oluwa,
Read hymn : WO b’ ikore tip oWO Imole! larin okun aiye, Ma sin mi lo. Okunkun su, mo si jina s’ ile, Ma sin mi lo.
Read hymn : WO Imole! larin okun aiyeWO kakiri f’ enit’ o s’ alaini, R’ enia lowo loni! Bi ‘ranlowo na si tile kere, R’ enia lowo loni!
Read hymn : WO kakiri f’ enit’ o s’ alainiWO oju sanma ohun ni. Wo lila orun oro. Ji l’ oju orun, okan mi, Dide k’ o si ma sora;
Read hymn : WO oju sanma ohun ni