JESU Or’ elese mo de
JESU Or’ elese mo de, Em’ otosi wa fun ‘rawo, Ara mi su mi fun ese, Na apa Re gba mi s’ ile.
Read hymn : JESU Or’ elese mo deJESU Or’ elese mo de, Em’ otosi wa fun ‘rawo, Ara mi su mi fun ese, Na apa Re gba mi s’ ile.
Read hymn : JESU Or’ elese mo deJESU o ye ki nl’ ayo, Ti mba le gbekele O, Pe ogbon Re to to mi, Pe ore Re to pese,
Read hymn : JESU o ye ki nl’ ayoJESU pe omode, O gbe won s’ aiya Re; O f’ owo Re gba won mora, O si sure fun won.
Read hymn : JESU pe omodeJESU ti mo gbeke mi le, At’ ireti mi lo s’ orun: Mo r’ ipa Re, ngo si tele Ona Re titi ngo fi ri.
Read hymn : JESU ti mo gbeke mi leJESU t’ asia Re bow a, O f’ onje m’ okan way o; O te ase siwaju wa, T’ a f’ eran ara Re se.
Read hymn : JESU t’ asia Re bow aJESU t’o k’o gb’aiye la, Jinde kuro ninu oku, Nipa agbara Re; A da, sile lowo iku,
Read hymn : JESU t’o k’o gb’aiye laJESU t’ O wa gba mi la, Wo ‘nu odo Jordani, O jade kuro n’nu re, A si m’ O l’ Om’-Olorun,
Read hymn : JESU t’ O wa gba mi laJESU wipe k’ a ma sora Ni wakati gbogbo, O si nf’ emi isoji fun Awon t’ o mbere re.
Read hymn : JESU wipe k’ a ma soraJESU ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n ‘ipa mo. – Alleluya!
Read hymn : JESU ye; titi aiyeJESU y’o joba ni gbogbo Ibit’ a ba le ri orun; ‘Joba Re y’o tan kakiri, ‘Joba Re ki o n’ ipekun.
Read hymn : JESU y’o joba ni gbogboJESU ‘ wo Onisegun nla, T’ olokunrun nf’ ailera mo, Nigba aisan at’ irora, O se dida ara fun won.
Read hymn : JESU ‘ wo Onisegun nlaJI, apa Olorun, k’ o ji, Gbe ‘pa Re wo, mi or’ ile; Ni sisin Re, je k’ aiye ri Isegun ise anu Re.
Read hymn : JI, apa Olorun, k’ o ji