ABA le n’ igbagbo aye
ABA le n’ igbagbo aye, B’ o ti wu k’ ota po; Igbagbo ti ko je mira Fun aini at’ os
Read hymn : ABA le n’ igbagbo ayeABA le n’ igbagbo aye, B’ o ti wu k’ ota po; Igbagbo ti ko je mira Fun aini at’ os
Read hymn : ABA le n’ igbagbo ayeIFE orun t’ o teriba Lati pin ninu ekun wa: Iwo l’ a k’ aniyan wa le, Ko si nkan gbat’ O sunmo wa.
Read hymn : IFE orun t’ o teribaISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yi, Emi o se kun, ‘gbat’ iyonu ba de; Simi okan mi, eyikeyi t’ o de, O dun ajo mi ku, o mu k’ ile ya.
Read hymn : ISIMI wa l’ orun, ko si l’ aiye yiIGBA wa mbe li owo Re, A fe ko wa nibe; A fie mi at’ ara wa Si abe iso Re.
Read hymn : IGBA wa mbe li owo ReNIHIN l’ ayida wa, Ojo, erun nkoja; Ile ni nyan, ti o si nsa, ‘Tana dada si nku;
Read hymn : NIHIN l’ ayida waA IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoiya ko si.
Read hymn : A IGBAGBO bila! T’ emi l’ OluwaOLORUN Olodumare, Alanu, Olore, Iwo l’ O da gbogbo aiye, Ati orun pelu.
Read hymn : OLORUN OlodumareOLUWA, ki s’agbara mi Bi mo ye, bi mo ku; Lati sin O ni ipin mi, Iwo ni si fun ni.
Read hymn : OLUWA, ki s’agbara miB’AIYE mi kun fun ‘banuje, O dara, o te mi l’orun; Laikun mo nreti ipe Re, Gbogbo nkan ni emi ntoro.
Read hymn : B’AIYE mi kun fun ‘banujeONA Re, Oluwa, B’ o ti wu k’ o su to, Masai f’ owo ‘tun Re to mi, Yan ipa mi fun mi.
Read hymn : ONA Re, OluwaMA toju, Jehofah nla, Ero l’ aiye osi yi, Emi ko l’ okun, iwo ni, F’ ow’ agbara di mi mu,
Read hymn : MA toju, Jehofah nlaBABA mi, ‘gba mo nsako lo, Kuro l’ ona Re l’ aiye yi; Ko mi kin le bayi pe, Se ‘fe Tire.
Read hymn : BABA mi, ‘gba mo nsako lo