A KO ni ‘bugbe kan nihin
A KO ni ‘bugbe kan nihin, Onile e roar yanran; B’ o fi gbogb’ aiye ko Garet, Ese mefa ni busun wa.
Read hymn : A KO ni ‘bugbe kan nihinA KO ni ‘bugbe kan nihin, Onile e roar yanran; B’ o fi gbogb’ aiye ko Garet, Ese mefa ni busun wa.
Read hymn : A KO ni ‘bugbe kan nihinAKO n’ ibugbe kan nihin, Eyi ba elese n’nu je; Ko ye k’ enia mimo kanu, ‘Tori nwon nfe ‘simi t’ orun.
Read hymn : AKO n’ ibugbe kan nihinALABUKUN n’ isun eje, T’ a fi han elese aiye; Olubukun n’ om Olorun, Nipa ‘na Re la wow a san,
Read hymn : ALABUKUN n’ isun ejeALABUKUN n’nu Jesu Ni awon om’ Olorun Ti a fie je Re ra Lati ‘nu iku s’ iye;
Read hymn : ALABUKUN n’nu JesuALAFIA, li aiye ese yi, Eje Jesu nwipe, “Alafia!”
Read hymn : ALAFIA, li aiye ese yiALAFIA pel’ Oluwa, A, ede wo l’ eyi! A f’ eje b’ elese la ‘ja, Oto ‘simi l’ eyi.
Read hymn : ALAFIA pel’ OluwaALAFIA w’ okan, t’ ohun re Ko apata l’ ohun aro: Dekun ejo wi, pa ‘nu mo, Ki ekun ye san l’ oju re;
Read hymn : ALAFIA w’ okan, t’ ohun reALAIMO lie mi, Olorun Oluwa! Emi ha gbodo sunmo O T’ emi t’ eru ese?
Read hymn : ALAIMO lie miALAKOSO ti orun, Alanu at’ Ologbon; Igba mi mbe l’ owo Re, Opin gbogbo l’ ase Re.
Read hymn : ALAKOSO ti orunALEJO kan ma nkankun, Pe E wole O ti npara ‘be tip e Pe E wole.
Read hymn : ALEJO kan ma nkankunALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d’ opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo l’ a o ma ko. Alleluya!
Read hymn : ALLELUYA! Alleluya!! Alleluya!!!AM’Oluwa iye Lo sinu ‘gbi mimo; Enit’ O wa gb’ okan wa la Ri l’ odo Jordani.
Read hymn : AM’Oluwa iye