Ko s’ ona si ayo orun
Ko s’ ona si ayo orun, S’ ayo at’ alafia toto, Lehin Jesu, Ona; Jek’ a rin l’ ona mimo na,
Read hymn : Ko s’ ona si ayo orunKo s’ ona si ayo orun, S’ ayo at’ alafia toto, Lehin Jesu, Ona; Jek’ a rin l’ ona mimo na,
Read hymn : Ko s’ ona si ayo orunKO s’ ore bi Jesu onirele, Ko s’ okan! Ko s’ okan! Ko s’ elomi t’ o le w’ okan wa san, Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Read hymn : KO s’ ore bi Jesu onireleKO to k’ awon mimo beru, Ki nwon so ‘reti nu; ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, Olugbala yio de.
Read hymn : KO to k’ awon mimo beruKRIST, ologo, olola, Iwo Imole aiye, Orun ododo, dide, K’ O si bori okunkun;
Read hymn : KRIST, ologo, ololaKRISTIAN ma ti wa ‘simi, Beli angeli re nwi, Ni arin ota l’ owa, Ma sora.
Read hymn : KRISTIAN ma ti wa ‘simi,KRISTI fun gbogb’ aiye Ise nla naa bere Egbegberun ni gbogb’ aiye, Nfe gb’ oro ‘mo ‘Lorun
Read hymn : KRISTI fun gbogb’ aiyeKRISTI n’ ipile wa, Lori Re lao kole; Awon mimo nikan, L’ o ngb’ agbala orun.
Read hymn : KRISTI n’ ipile waKRIST’, nin’ ogba Eden, L’ a gbe ti ri r’ ase yi, Ase Tire, P’ o ye f’ eni meji
Read hymn : KRIST’, nin’ ogba EdenKRIST’ ki ‘joba Re de, Ki ase Re bere; F’ opa-rin Re fo Gbogbo ipa ese.
Read hymn : KRIST’ ki ‘joba Re deKRIST’ Oluwa ji loni, – Halleluyah, Eda at’ Angeli nwi – Hal. Gb’ ayo at’ isegun ga – Hal. K’ orun at’ aiye gberin! – Hal.
Read hymn : KRIST’ Oluwa ji loni, – HalleluyahK’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la.
Read hymn : K’ A to sun, Olugbala waK’ OLORUN so o, k’ a tun pade Ki imoran Re gbe o ro, K’ O ka o mo agutan Re, K’ Olorun so o, k’ a tun pade!
Read hymn : K’ OLORUN so o, k’ a tun pade