BAWO ni awon ewe wa
BAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,”
Read hymn : BAWO ni awon ewe waBAWO ni awon ewe wa, Y’o ti ma sora won; Bikose “nipa ‘kiyesi, Gege bi oro Re,”
Read hymn : BAWO ni awon ewe waBIBEL’ iwe aiyeraiye Tani le ridi re? Tani le so idide re? Tani le m’ opin re?
Read hymn : BIBEL’ iwe aiyeraiyeIWO Oro Olorun, Ogbon at’ oke wa, Oto ti ki ‘yipada, Imole aiye wa;
Read hymn : IWO Oro OlorunIWE kan wa ti kika ra, Ko soro fun enia, Ogbon ti awon t’o ka nfe, Ni okan ti o mo.
Read hymn : IWE kan wa ti kika raTORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo;
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrereIWO oro t’o tobi, Ninu eyit ‘a ri, Ileri ati sise Awamaridi ni:
Read hymn : IWO oro t’o tobiJESU, Oba nla ni Sion, ‘Wo ni yio j’ amona wa; Ase Re li a gbekele, Iwo nikan l’ ao tele.
Read hymn : JESU, Oba nla ni SionJESU mo bg’ agbelebu mi, Ki nle ma to O lehin; Otosi at’ eni egan, ‘Wo l’ ohun gbogbo fun mi;
Read hymn : JESU mo bg’ agbelebu miENI ‘rele, t’ o nwa ‘gbala Nip’ eje Od’-agutan, E gbo ohun isipaya, Erin ‘na ti Jesu rin.s
Read hymn : ENI ‘rele, t’ o nwa ‘gbalaAM’Oluwa iye Lo sinu ‘gbi mimo; Enit’ O wa gb’ okan wa la Ri l’ odo Jordani.
Read hymn : AM’Oluwa iyeN’IFE l’ a te ona T’ Olugbala ti rin; A f’ apere Olori wa, Agutan Olorun.
Read hymn : N’IFE l’ a te onaL’ONA gbogbo t’ Oluwa yan, Ajo mi l’ emi o to; Ma da mi ro, eyin mimo, Emi o ban yin lo.
Read hymn : L’ONA gbogbo t’ Oluwa yan