MA koja mi, Olugbala
MA koja mi, Olugbala, Gbo adura mi; ‘Gbat’ Iwo ba np’ elomiran, Mase koja mi!
Read hymn : MA koja mi, OlugbalaMA koja mi, Olugbala, Gbo adura mi; ‘Gbat’ Iwo ba np’ elomiran, Mase koja mi!
Read hymn : MA koja mi, OlugbalaWO ‘le ‘wo enit’ a bukun, O ki tun s’ alajo; A fi gbogbo okan gba o, ‘Wo arakunrin wa.
Read hymn : WO ‘le ‘wo enit’ a bukunARA n’nu Krist’, nitori Re, A fi t’ okantokan gba o; K’ a le jumo je ayo ti Ko s’ en’ti fun ni lehin Re.
Read hymn : ARA n’nu Krist’, nitori ReWO ‘le, ‘wo alabukunfun; Wa l’ oruko Jesu owon; A f’ ohun kan ke, “Ma wole,” A ro pe Jesu kio pelu.
Read hymn : WO ‘le, ‘wo alabukunfunENYIN enia Olorun, Mo ti kiri aiye ka, To ‘pa ese on ‘kanu, Nko r’ itunu n’ ibikan.
Read hymn : ENYIN enia OlorunJESU, ‘ Wo Olus’-agutan, Pa agbo Re kekere mo; Gb’ awon agutan Re wonyi, Ma jekii nwon ko gbo lai.
Read hymn : JESU, ‘ Wo Olus’-agutanJI ‘se Re nde Jesu! Fi agbara Re han! Fo ‘hun t’ o le j’ oku dide Je k’ enia Re gbo.
Read hymn : JI ‘se Re nde Jesu!MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese ni Isegun kan yio f’ ipa miran fun o Ma ja bi okunrin, segun ibinu Ma tejumo Jesu, yio mu o la ja
Read hymn : MA f’ ara fun ‘danwo, nitor’ ese niA, JESU Alabukun, A m’ orin ayo wa, Ohun at’ okan ‘pe wa L’ ayo l’ a gbe si O;
Read hymn : A, JESU AlabukunTO nwon, Baba si O, To nwon si O; Awon omo wonyi Ti O fun ni,
Read hymn : TO nwon, Baba si OOLUWA sokale, Bukun awon ‘mo ma, Laipe, ki ife won le te Si ore-ofe Re.
Read hymn : OLUWA sokaleE DIDE ki a si lorin, K’ a yin Oluwa wa, K’ a si dupe li owo Re, F’ anfani idasi.
Read hymn : E DIDE ki a si lorin