OSE, ose t’ a nret
OSE, ose t’ a nreti A ki o pe “Ma wole,” Iwo ni idunnu wa, A kio s’ ole ninu re.
Read hymn : OSE, ose t’ a nretOSE, ose t’ a nreti A ki o pe “Ma wole,” Iwo ni idunnu wa, A kio s’ ole ninu re.
Read hymn : OSE, ose t’ a nretLEHIN ‘jo mefa t’ O sise, O simi ni ijo keje, O pase fun wa k’ a se be, Ki a si pa ojo na mo.
Read hymn : LEHIN ‘jo mefa t’ O siseJESU Oba, a pari eko wa, Ma jeki Esu sa je l’ okan wa.
Read hymn : JESU Oba, a pari eko waK AWA to pari eko wa, Awa f’ iyin fun O; ‘Tori ojo Re mimo yi, Jesu Ore ewe.
Read hymn : K AWA to pari eko waMO fe ki ndabi Jesu, Ninu iwa pele; Ko s’ enit’ o gboro ‘binu L’ enu Re lekan ri.
Read hymn : MO fe ki ndabi JesuBI osun gbege eti ‘do, Tutu minimini; B’ igbo dudu eti omi, B’ itanna ipa ‘do.
Read hymn : BI osun gbege eti ‘doILE-EKO ojo ‘sinmi, A, mo ti fe O to! Inu mi dun mo daraya Lati yo ayo re
Read hymn : ILE-EKO ojo ‘sinmiOLORUN Baba, Krist’ Omo, Ati Emi, Metalokan, Gba ore ti a mu wa yi, T’ a f’ ife onigbagbo se.
Read hymn : OLORUN Baba, Krist’ OmoNIHIN, l’ oko Re Oluwa, A ko ‘le ‘rupe yi fun O, Yan fun ‘bugbe Re Pataki, K’ O si so lowo asise.
Read hymn : NIHIN, l’ oko Re OluwaOLORUN Baba, Ologo, T’ O joko lor’ ite lai, Awa omo Re teriba, A nw’ ojure Re nikan;
Read hymn : OLORUN Baba, OlogoKRISTI n’ ipile wa, Lori Re lao kole; Awon mimo nikan, L’ o ngb’ agbala orun.
Read hymn : KRISTI n’ ipile waLAT’ oke tutu Grinland, Lati okun india, Nib’ odo orun Afrik’, Nsan ‘yanrin wura won;
Read hymn : LAT’ oke tutu Grinland