GBO ohun Jesu ti nke pe
GBO ohun Jesu ti nke pe, Tani yio sise loni? Oko pon pupo sise loni? Tani yio lo ka a?
Read hymn : GBO ohun Jesu ti nke peGBO ohun Jesu ti nke pe, Tani yio sise loni? Oko pon pupo sise loni? Tani yio lo ka a?
Read hymn : GBO ohun Jesu ti nke peIWO ti okunkun Gb’ oro agbara Re, T’ o si fo lo; Gbo ti wa, a mbe O,
Read hymn : IWO ti okunkunKEFERI nsegbe lojojo, Egbegberun l’ o nkoja lo; Mura Kristian s’igbala won, Wasu fun won ki nwon to ku.
Read hymn : KEFERI nsegbe lojojoWA, ma sise, Tani gbodo s’ole ninu oko, Gbati gbogbo enia nkore jo? Kaluku ni Baba pase fun pe, –
Read hymn : WA, ma siseWO b’ ikore tip o L’ otun l’ osi wa, Alagbase kere L’ ogba Oluwa,
Read hymn : WO b’ ikore tip oEFUN ‘pe na kikan, Ipe ihinrere, K’ o dun ja ‘ke ja ‘do, L’ eti gbogbo eda;
Read hymn : EFUN ‘pe na kikanIRANSE Oluwa! E duro nid’ ise; E toju oro Re mimo, E ma sona Re sa,
Read hymn : IRANSE OluwaMA sise lo, mase sare, Fi ayo sise Baba re; Bayi ni Jesu se l’ aiye Ko ha ye k’ awa ko se be?
Read hymn : MA sise lo, mase sareJESU y’o joba ni gbogbo Ibit’ a ba le ri orun; ‘Joba Re y’o tan kakiri, ‘Joba Re ki o n’ ipekun.
Read hymn : JESU y’o joba ni gbogboGBO! Orin ti Jubili, O dabi sisan ara; Tabi bi kikun okun, Gbat’ igbi re ba nlu ‘le
Read hymn : GBO! Orin ti JubiliFUNRUGBIN l’ owuro, Ma simi tit’ ale; F’ eru on ‘yemeji sile Ma fon s’ ibi gbogbo.
Read hymn : FUNRUGBIN l’ owuroORO die fun Jesu; Ore otito ni; Wa tu okan wa ninu Ohun t’o se fun o.
Read hymn : ORO die fun Jesu