ODUN miran ti koja
ODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo;
Read hymn : ODUN miran ti koja643 hymns
ODUN miran ti koja, Wawa l’ akoko na lo, Ninu eyit’ a wa yi, Yio se arimo opo;
Read hymn : ODUN miran ti kojaOGABJO gan: l’ oke Olif’ Awon irawo si ti wo; Oganjo gan: nisisyi Jesu nikan ngbadura l’ ogba.
Read hymn : OGABJO gan: l’ oke OlifOGO f’ Olorun l’ ale yi Fun gbogbo ore imole, So mi, Oba awon oba Labe ojiji iye Re.
Read hymn : OGO f’ Olorun l’ ale yiOG’ Oluwa j’ ohun ‘yanu, Ona Re si yato; Ko si j’ ohun t’ o wu eda, Lati fi iyin fun.
Read hymn : OG’ Oluwa j’ ohun ‘yanuOHUN ipe kan ti, oke petele wa, S’ olotito, ‘lotito, ‘lotito si Krist, Oke gba orin na, gege b’o ti ndun lo, T’ olotito, ‘lotito, A! ‘lotito si Krist.
Read hymn : OHUN ipe kan ti, oke petele waOHUN ogo Re l’ a nrohin, Sion’ ti Olorun wa; Oro Enit’ a ko le ye, Se o ye fun ‘bugbe Re,
Read hymn : OHUN ogo Re l’ a nrohinOHUN tin dun l’ aginju, Ohun alore ni, Gbo b’ o tin dun rara pe, “E ronupiwada.”
Read hymn : OHUN tin dun l’ aginjuOJISE Krist’, dide, E mura fun ‘se na, Iri ‘bukun lat’ orun wa Ti se s’ ori ile.
Read hymn : OJISE Krist’, dideOJO ayo l’ ojo ti mo Yan O, ‘Wo Olugbala mi; O to ki okan mi ko yo, K’ o si s’ ayo re kakiri
Read hymn : OJO ayo l’ ojo ti moOJO ayo nlanla na de, Eyit’ araiye ti nreti; Nigbat’ Olugbala w’ aiye, Nigbat’ a bi ninu ara.
Read hymn : OJO ayo nlanla na deOJO ibukun yio sir o!” Eyi n’ ileri ife; A o ni itura didun Lat’ odo Olugbala
Read hymn : OJO ibukun yio sir oOJO mefa t’ ise koja, Okan t’ isimi si bere; Pada okan mi wa ‘simi, Yo s’ ojo t’ Oluwa busi.
Read hymn : OJO mefa t’ ise koja