A NT’ ona t’ Oluwa war in
A NT’ ona t’ Oluwa war in: A ngb’ agbelebu Re; Gbogb’ egun t’o ngun wa l’ese Ti gun l’ori saju.
Read hymn : A NT’ ona t’ Oluwa war inA NT’ ona t’ Oluwa war in: A ngb’ agbelebu Re; Gbogb’ egun t’o ngun wa l’ese Ti gun l’ori saju.
Read hymn : A NT’ ona t’ Oluwa war inAO ha pade l’ eti odo, T’ ese angeli ti te, ‘T o mo gara bi kristali, Leba ite Olorun?
Read hymn : AO ha pade l’ eti odoAO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni wa, Jek’ a tele ona ti Oluwa wa to; K’ a f’ imoran Re so agbara wa d’ otun, K’ a fi gbogbo okun wa sise t’ a o se.
Read hymn : AO sise ! ao sise! Om’ -Olorun ni waAPATA aiyeraiye, Se ibi isadi mi! Je ki omi on eje T’ o san lati iha Re
Read hymn : APATA aiyeraiyeAPATA aiyeraiye, Enit’ o mbe lailai, Nigbakugba t’ iji nja, ‘Bugbe wa y’o gbe je:
Read hymn : APATA aiyeraiyeAPATA wa n’ ile are, Ojiji Re bo si iyanrin, O npe awon ero ti nkoja, Lati wa si boji l’ aginju.
Read hymn : APATA wa n’ ile areARA, b’ a ko tile gbo Ohun kan lat’ oke wa; Sibe a mo pe loni, Gbogbo ‘rora tan fun o.
Read hymn : ARA, b’ a ko tile gboA RA, e wa ba mi s’ ofo, E wa sodo Olugbala; Wa, e je k’ a jumo s’ ofo; A kan Jesu m’ agbelebu.
Read hymn : A RA, e wa ba mi s’ ofoARA e jek’ a jumo rin N’ ife on alafia; A ha le ma tun bere pe, O to k’ a ba f’ ija mo?
Read hymn : ARA e jek’ a jumo rinARA mi fun ‘rugbin rere, Nigba ifunrugbin wa, Ma sise l’ oruko Jesu, Tit’ On o tun pada, wa,
Read hymn : ARA mi fun ‘rugbin rereARA n’nu Krist’, nitori Re, A fi t’ okantokan gba o; K’ a le jumo je ayo ti Ko s’ en’ti fun ni lehin Re.
Read hymn : ARA n’nu Krist’, nitori ReARE mu o, aiye su o, Lala po fun o? Jesu ni, “Wa si odo, Mi, K’ o simi.”
Read hymn : ARE mu o, aiye su o