ALAKOSO ti orun
ALAKOSO ti orun, Alanu at’ Ologbon; Igba mi mbe l’ owo Re, Opin gbogbo l’ ase Re.
Read hymn : ALAKOSO ti orunALAKOSO ti orun, Alanu at’ Ologbon; Igba mi mbe l’ owo Re, Opin gbogbo l’ ase Re.
Read hymn : ALAKOSO ti orunOLUWA alafia wa L’ O pase t’ odun yipo; Awa omo Re wa dupe F’ odun titun t’ a bere.
Read hymn : OLUWA alafia waOLORUN t’ odun tr’ o koja, Iret’ eyi ti mbo; Ib’ isadi wa ni iji, At’ ile wa lailai.
Read hymn : OLORUN t’ odun tr’ o kojaB’ ORUN l’ aiduro ti rin, La odun ti o lo ja Be l’ opo ti d’ opin won A ki o si ri won mo.
Read hymn : B’ ORUN l’ aiduro ti rinOLUWA at’ ‘igbala wa, L’ o ko wa jo l’ ale oni, Je ka gbe Ebeneser ro; Odun t’ a ti la koja yi,
Read hymn : OLUWA at’ ‘igbala waNI akoko ipinya, Jeki a fi ara wa, S’ abe oju at’ okan, Ore korikosun wa.
Read hymn : NI akoko ipinyaAO ha pade l’ eti odo, T’ ese angeli ti te, ‘T o mo gara bi kristali, Leba ite Olorun?
Read hymn : AO ha pade l’ eti odoK’ OLORUN so o, k’ a tun pade Ki imoran Re gbe o ro, K’ O ka o mo agutan Re, K’ Olorun so o, k’ a tun pade!
Read hymn : K’ OLORUN so o, k’ a tun padeNIHIN l’ awa nje ‘rora, Nihin ni a ma pinya, L’ orun ko si ‘pinya, A! bi yio ti dun to!
Read hymn : NIHIN l’ awa nje ‘roraK’ ORE-ofe Krist’ Oluwa, Ife Baba ailopin, Oju rere Emi Mimo K’ o t’ oke ba lori wa.
Read hymn : K’ ORE-ofe Krist’ OluwaOLORUN l’ odo eniti ‘Toju ife ti nwa, Iforiti gbagbo ‘reti, Ro ‘jo won lat’ oke.
Read hymn : OLORUN l’ odo enitiJESU awa nwo O fun ‘Wosan alailera yi ‘Wo lo ti se anu nla, F’ abiirun let’ adagun.
Read hymn : JESU awa nwo O fun