JESU ‘ wo Onisegun nla
JESU ‘ wo Onisegun nla, T’ olokunrun nf’ ailera mo, Nigba aisan at’ irora, O se dida ara fun won.
Read hymn : JESU ‘ wo Onisegun nlaJESU ‘ wo Onisegun nla, T’ olokunrun nf’ ailera mo, Nigba aisan at’ irora, O se dida ara fun won.
Read hymn : JESU ‘ wo Onisegun nlaMO gbeke mi le O, Lori ibusun mi, Gba mi lowo irora mi, Ki O si wo mi san.
Read hymn : MO gbeke mi le OISE re Oluwa, Awamaridi ni, Ohun gbogbo ni mu ‘re wa, F’ eni to se ‘fe Re.
Read hymn : ISE re OluwaB’ ODO ti nyara san lo, Li ona gboro re, Ti omi re nja titi, T’ o nsare lo s’ okun,
Read hymn : B’ ODO ti nyara san loKO mi ni iwon ojo mi, Iwo Eleda mi; Mo fe w’ ona toro aiye, Ki nmo ailera mi.
Read hymn : KO mi ni iwon ojo miOLORUN lat’ irandiran, ‘Wo n’ isimi at’ abo wa, K’ a to da orun at’ aiye, Giga ni ife Re l’ oke.
Read hymn : OLORUN lat’ irandiranLAB’ ese, ati l’ oke wa, Ni ikilo tin dun, Oku aimo ‘ye sun n’nu ‘le, Orun si wa l’ oke.
Read hymn : LAB’ ese, ati l’ oke waILE ‘simi, mo nreti re, ‘Gbawo n’ igba yio de, Ti ngo bo ‘hamora sile, Ti ngo wa pelu Krist”?
Read hymn : ILE ‘simi, mo nreti reAKOKO ati lo mi ya, Mo gb’ ohun to npe mi lo ‘le, Olorun jek’ iyonu pin, Jek’ iranse Re ku l’ ayo.
Read hymn : AKOKO ati lo mi yaARA, b’ a ko tile gbo Ohun kan lat’ oke wa; Sibe a mo pe loni, Gbogbo ‘rora tan fun o.
Read hymn : ARA, b’ a ko tile gboGB’ ohun t’ o orun wa ti wi F’ awon mimo t’ o ku, “Didun l’ orun oruko won, ‘Busun won n’ itura.”
Read hymn : GB’ ohun t’ o orun wa ti wiKIKU n’nu Jesu, iku re T’ a ki ji sinu re sokun, Isimi t’ o ni itura, Ti iku ko le yo lenu.
Read hymn : KIKU n’nu Jesu, iku re