OKAN mi pe ninu Jesu
OKAN mi pe ninu Jesu: Ko beru ise ofin mo; Erin Olorun dun ninu, Nibit’ o ti kun f’ ese ri.
Read hymn : OKAN mi pe ninu JesuOKAN mi pe ninu Jesu: Ko beru ise ofin mo; Erin Olorun dun ninu, Nibit’ o ti kun f’ ese ri.
Read hymn : OKAN mi pe ninu JesuOKAN mi yin Oba orun, Mu ore wa sodo Re; ‘Wo t’ a wo san, t’ a dariji, Tal’ a ba ha yin bi Re?
Read hymn : OKAN mi yin Oba orunOKAN wa ji; k’ eru fo lo, Ki gbogbo ifoiya k’o lo; Ji, k’ o sis are ‘je orun, Si fi igboiya ayo han.
Read hymn : OKAN wa ji; k’ eru fo loOKE kan mbe jina rere, Lehin odi ilu, Nibit’ a kan Oluwa mo, Enit’ O ku fun wa.
Read hymn : OKE kan mbe jina rereOku! – Ore elese ku Omobirin Salem’ Sokun; Okunkun bo oju orun, Ile wariri lojiji.
Read hymn : Oku! – Ore elese kuOLORI ijo t’ orun, L’ ayo l’ a wole fun O; K’ o to de, ijo t’ aiye, Y’o ma korin bi t’ orun,
Read hymn : OLORI ijo t’ orunOLORUN! Kini mo ri yi! Opin de f’ohun gbogbo! Onidajo araiye yo, O gunwa n’ite ‘dajo
Read hymn : OLORUN! Kini mo ri yiOLORUN awa fe, Ile t’ ola Re wa; Ayo ibugbe Re Ju gbogbo ayo lo.
Read hymn : OLORUN awa feOLORUN Baba, Krist’ Omo, Ati Emi, Metalokan, Gba ore ti a mu wa yi, T’ a f’ ife onigbagbo se.
Read hymn : OLORUN Baba, Krist’ OmoOLORUN Baba, Ologo, T’ O joko lor’ ite lai, Awa omo Re teriba, A nw’ ojure Re nikan;
Read hymn : OLORUN Baba, OlogoOLORUN Bethel, Eniti O mbo awon Tire; Enit’ o mu baba wa la Ojo aiye won ja.
Read hymn : OLORUN Bethel, EnitiOLORUN emi wa, at’ igbala wa, ‘Mole okunkun wa, ‘reti ile wa, Gbo, ki O si gba ebe ijo Re yi, Olodumare.
Read hymn : OLORUN emi wa, at’ igbala wa