OLORUN emi wa, at’ igbala wa
OLORUN emi wa, at’ igbala wa, ‘Mole okunkun wa, ‘reti ile wa, Gbo, ki O si gba ebe ijo Re yi, Olodumare.
Read hymn : OLORUN emi wa, at’ igbala wa643 hymns
OLORUN emi wa, at’ igbala wa, ‘Mole okunkun wa, ‘reti ile wa, Gbo, ki O si gba ebe ijo Re yi, Olodumare.
Read hymn : OLORUN emi wa, at’ igbala waOLORUN fe araiye, O fe tobe ge, T’ O ran Omo Re w’ aiye T’ O ku fun elses;
Read hymn : OLORUN fe araiyeOLORUN kutu ohun Re L’ o mu orun f’ ayo dide, Inu re dun bi omiran, Lati sare yi sanma ka.
Read hymn : OLORUN kutu ohun ReOLORUN lat’ irandiran, ‘Wo n’ isimi at’ abo wa, K’ a to da orun at’ aiye, Giga ni ife Re l’ oke.
Read hymn : OLORUN lat’ irandiranOLORUN lat’ oro d’ ale, Wakati wo l’ o dun pupo, B’ eyi t’ o pe mi wa ‘do Re Fun adua?
Read hymn : OLORUN lat’ oro d’ aleOLORUN l’ abo eni Re, Nigba iji iponju de: K’ awa to se aroye wa, A! saw o t’ On t’ iranwo Re.
Read hymn : OLORUN l’ abo eni ReOLORUN l’ odo eniti ‘Toju ife ti nwa, Iforiti gbagbo ‘reti, Ro ‘jo won lat’ oke.
Read hymn : OLORUN l’ odo enitiOLORUN mi bojuwo mi F’ iyanu ‘fe nla Re han mi; Ma je ki ngbere fun ‘ra mi, Tori ‘Wo si ngbero fun mi;
Read hymn : OLORUN mi bojuwo miOLORUN mi! Olorun mi! Mo f’ ara mi fun O; Dari aisedede ji mi, Ma je ki nsako mo,
Read hymn : OLORUN mi! Olorun miOLORUN npe, ngo ha s’ aigbo? Ngo ha s’ afe aiye d’ owon? Odun y’o ha ma rekoja K’ okan mi ma togbe sibe?
Read hymn : OLORUN npe, ngo ha s’ aigboOLORUN Olodumare, Alanu, Olore, Iwo l’ O da gbogbo aiye, Ati orun pelu.
Read hymn : OLORUN OlodumareOLORUN Olurapada, Mo ri ‘se mi nin’ oro Re, Ninu ‘gbe aiye Re nihin, Ofin f’ ara han gedegbe.
Read hymn : OLORUN Olurapada