OLUWA, y’o ti pe to
OLUWA, y’o ti pe to T’ Iwo o tun pada; Are fere mu wa tan, Bi a ti nw’ ona Re;
Read hymn : OLUWA, y’o ti pe to643 hymns
OLUWA, y’o ti pe to T’ Iwo o tun pada; Are fere mu wa tan, Bi a ti nw’ ona Re;
Read hymn : OLUWA, y’o ti pe toOLUWA, ‘gbat’ a ngbadura Fun gbogbo enia, Gb’adura wa fun ile wa, Ile t’ a fe julo.
Read hymn : OLUWA, ‘gbat’ a ngbaduraOMO Olorun nlo s’ ogun Lati gb’ ade Oba: Opagun Re si nfe, lele, Tal’ o s’ om-ogun Re?
Read hymn : OMO Olorun nlo s’ ogunOM’ Olorun, a ko ri O, ‘Gbat’ O wa s’ aiye iku yi; Awa ko ibugbe Re, Ni Nasareti ti a gan;
Read hymn : OM’ Olorun, a ko ri OOM’-OGUN Krist’ dide Mu ‘hamora nyin wo; Mu ‘pa t’ Olorun fi fun nyin, Nipa ti Omo Re.
Read hymn : OM’-OGUN Krist’ dide.ONA ara l’ Olorun wa Ngba sise Re l’ aiye; A nri ‘pase Re lor’ okun, O ngun igbi l’ esin.
Read hymn : ONA ara l’ Olorun waONA Re, Oluwa, B’ o ti wu k’ o su to, Masai f’ owo ‘tun Re to mi, Yan ipa mi fun mi.
Read hymn : ONA Re, OluwaONIGBAGBO, e bu s’ ayo! Ojo nla l’ eyi fun wa; K’ orun f’ ayo korin kikan, K’ igbo at’ odan gberin.
Read hymn : ONIGBAGBO, e bu s’ ayoONIGBAGBO, e wo Oluwa nyin n’nu ‘se, A ri s inu okun ‘rora, T’ o b’ okan Re mo ‘le.
Read hymn : ONIGBAGBO, e woONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu!
Read hymn : ONISEGUN nla wa nihinONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu!
Read hymn : ONISEGUN nla wa nihinONTO mi lo iro ‘bukun, Oro t’ orun tu mi ninu, Ohun ti o wu kemi se Sibe Olorun nto mi lo.
Read hymn : ONTO mi lo iro ‘bukun