IGBAGBO l’ ategun t’ o so
IGBAGBO l’ ategun t’ o so Orun at’ aiye po; On l’ Olugbala fi sise Iyanu Re l’ aiye.
Read hymn : IGBAGBO l’ ategun t’ o soIGBAGBO l’ ategun t’ o so Orun at’ aiye po; On l’ Olugbala fi sise Iyanu Re l’ aiye.
Read hymn : IGBAGBO l’ ategun t’ o soOLORI ijo t’ orun, L’ ayo l’ a wole fun O; K’ o to de, ijo t’ aiye, Y’o ma korin bi t’ orun,
Read hymn : OLORI ijo t’ orunOLORUN fe araiye, O fe tobe ge, T’ O ran Omo Re w’ aiye T’ O ku fun elses;
Read hymn : OLORUN fe araiyeNIHIN l’ Olorun sin mi de, De ‘hin n’ ipa Re sun ‘jo mi, Gbogbo asale yio si fi Ami ore Re titun han.
Read hymn : NIHIN l’ Olorun sin mi deLARIN ewu at’ osi, Kristian, ma te siwaju, Roju duro, jija na, K’ onje ‘ye mu o l’ okun.
Read hymn : LARIN ewu at’ osi.EREDI iwa s’ aiye mi? ‘Tori kil’ a bi mi? Gbogb’ ohun l’ aiye l’ o n’ idi, Kil’ a ha da mi fun?
Read hymn : EREDI iwa s’ aiye miJEJE, lai si ariwo, Jeje li orun nran, Gbat’ o bay o n’ ila re, Eda le w’ oju re;
Read hymn : JEJE, lai si ariwoOLUWA, iji nfe s’ oke! Igbi omi nru s’ oke! Oju orun pelu su dudu, ‘Ranlowo ko si n’ tosi;
Read hymn : OLUWA, iji nfe s’ okeOJO ibukun yio sir o!” Eyi n’ ileri ife; A o ni itura didun Lat’ odo Olugbala
Read hymn : OJO ibukun yio sir oGBA Jesu ba de lati pin ere, B’ o j’ osan tabi l’ oru, Y’o ha ri wa nibit’ a gbe ns’ ona, Pel’ atupa wa tin tan?
Read hymn : GBA Jesu ba de lati pin ereLAB’ agbelebu Jesu Mo fe lati duro, – Oji apata titobi Ninu ile are,
Read hymn : LAB’ agbelebu JesuFUN mi n’ iwa pele, Okan tutu; Ifarabale bi T’ Oluwa mi;
Read hymn : FUN mi n’ iwa pele