L’ AYO l’ a ro t’ ore-ofe
L’ AYO l’ a ro t’ ore-ofe Alufa wa l’ oke; Okan Re kun fun iyonu, Aiya Re ntan fun ‘fe.
Read hymn : L’ AYO l’ a ro t’ ore-ofeL’ AYO l’ a ro t’ ore-ofe Alufa wa l’ oke; Okan Re kun fun iyonu, Aiya Re ntan fun ‘fe.
Read hymn : L’ AYO l’ a ro t’ ore-ofeORE-OFE! Ohun Adun ni l’ eti wa; Gbongbon re yio gba orun kan, Aiye o gbo pelu.
Read hymn : ORE-OFE! OhunONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu!
Read hymn : ONISEGUN nla wa nihinKO to k’ awon mimo beru, Ki nwon so ‘reti nu; ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, Olugbala yio de.
Read hymn : KO to k’ awon mimo beruJESU fe mi, emi mo; Bibeli so fun mi be; Tire l’ awon omode, Nwon ko l’ agbara, On ni.
Read hymn : JESU fe mi, emi moJESU l’ Olusagutan mi, Ore Eniti ki ye! Ko s’ ewu bi mo je Tire, T’ On sije t’ emi titi.
Read hymn : JESU l’ Olusagutan miNINU oru ibanuje, L’ awon egbe ero ayo, Nwon nkorin ‘reti at’ ayo, Nwon nlo s’ ile ileri.
Read hymn : NINU oru ibanujeOLORUN emi wa, at’ igbala wa, ‘Mole okunkun wa, ‘reti ile wa, Gbo, ki O si gba ebe ijo Re yi, Olodumare.
Read hymn : OLORUN emi wa, at’ igbala waJESU ma to wa Tit’ ao fi simi; Bi ona wa ko tile dan, A o tele O l’ aifoya;
Read hymn : JESU ma to waA JESU, Iwo nduro Lode, lehin ‘lekun, Iwo fi suru duro Lati koja s’ ile;
Read hymn : A JESU, Iwo nduroONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu!
Read hymn : ONISEGUN nla wa nihinENIKAN mbe t’ O feran wa, A! O fe wa! Ife Re ju t’ iyekan lo, A! O fe wa!
Read hymn : ENIKAN mbe t’ O feran wa