ARA n’nu Krist’, nitori Re
ARA n’nu Krist’, nitori Re, A fi t’ okantokan gba o; K’ a le jumo je ayo ti Ko s’ en’ti fun ni lehin Re.
Read hymn : ARA n’nu Krist’, nitori Re643 hymns
ARA n’nu Krist’, nitori Re, A fi t’ okantokan gba o; K’ a le jumo je ayo ti Ko s’ en’ti fun ni lehin Re.
Read hymn : ARA n’nu Krist’, nitori ReARA, b’ a ko tile gbo Ohun kan lat’ oke wa; Sibe a mo pe loni, Gbogbo ‘rora tan fun o.
Read hymn : ARA, b’ a ko tile gboARE mu o, aiye su o, Lala po fun o? Jesu ni, “Wa si odo, Mi, K’ o simi.”
Read hymn : ARE mu o, aiye su oASAN n’ ireti t’ enia ko Le ori ise won: A bi won pel’ okan eri, Ebi si n’ iwa won.
Read hymn : ASAN n’ ireti t’ enia koASORO ile ‘bukun ni Ile didan, at’ ile ewa ‘Gbagbogbon l’ a nso t’ogo re; Y’o ti dun to lati de ‘be!
Read hymn : ASORO ile ‘bukun niATI gbo iro didun, Jesu le gba ni la, Ji ‘se na yi aiye ka, Jesu le gba ni la,
Read hymn : ATI gbo iro didunAWA nbebe fun ‘le wa, Ki Afrika ko pe; K’ Olorun Olodumare, Fi alafia fun u.
Read hymn : AWA nbebe fun ‘le waAWON mimo! Ija nwon pin, Nwon segun aiye nikehin, Nwon ko fe ohun ija mo; Nwon da won si ese Jesu;
Read hymn : AWON mimo! Ija nwon pinAYIN O, Oluranwo wa, T’ife Re wa bakanna lai, Owo ike en’t’ o bere, Ti o si pari odun wa.
Read hymn : AYIN O, Oluranwo waAYO awon ti to, T’ o gb’ Olugbala gbo, T’o to isura nwon si oke Ahon ko le s’ adun
Read hymn : AYO awon ti toAYO b’ aiye: Oluwa de! K’ aiye gba Oba re; K’ okan gbogbo pes’ aye fun, Ki gbogb’ eda korin.
Read hymn : AYO b’ aiye: Oluwa deAYO kun okan wa loni A bi Omo Oba; Opo awon ogun orun, Nso t’ ibi Re loni:
Read hymn : AYO kun okan wa loni