OLUWA wow a l’ ese Re
OLUWA wow a l’ ese Re Otosi elese; Gege bi eniti nbebe, A wa ni ase Re.
Read hymn : OLUWA wow a l’ ese ReOLUWA wow a l’ ese Re Otosi elese; Gege bi eniti nbebe, A wa ni ase Re.
Read hymn : OLUWA wow a l’ ese ReSI pepe Oluwa, Mo mu ‘banuje wa; ‘Wo ki f’ anu tewogba Ohun alaiye yi?
Read hymn : SI pepe OluwaMOKANDILOGORUN dubule je, Labe oji nin’ agbo; Sugbon okan je lo s’ or’ oke, Jina s’ ilekun wura;
Read hymn : MOKANDILOGORUN dubule jeMO fe gbo itan kanna T’ awon Angeli-nso; Bi Oba Ogo ti wa, Gbe aiye osi yi;
Read hymn : MO fe gbo itan kannaWA, enyin olope, wa, Gbe orin ikore ga; Ire gbogbo ti wole K’ otutu oye to de;
Read hymn : WA, enyin olope, waOHUN ogo Re l’ a nrohin, Sion’ ti Olorun wa; Oro Enit’ a ko le ye, Se o ye fun ‘bugbe Re,
Read hymn : OHUN ogo Re l’ a nrohinOLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi;
Read hymn : OLUWA ni ObaYO, eyin onigbagbo, Je k’ imole nyin tan; Igba ale mbo tete, Oru si fere de.
Read hymn : YO, eyin onigbagboMO feran iwe oro Re; O f’ imole at’ ayo fun Okan okun on ‘banuje! Oro Re t’ oan mi wiwo;
Read hymn : MO feran iwe oro ReJESU, aso ododo Re L’ ewa at’ ewu ogo mi, L’ aiye etan bi mba gbe wo, L’ ayo ni ngo gb’ ori s’ oke.
Read hymn : JESU, aso ododo ReWA ba mi gbe! ale fere le tan, Okunkun nsu; Oluwa ba mi gbe, Bi oluranlowo miran ba ye, Iranwo alaini, wa ba mi gbe.
Read hymn : WA ba mi gbe! ale fere le tanBABA orun! Emi fe wa N’ iwa mimo, l’ ododo; Sugbon ife eran’-ara Ntan mi je nigbagbogbo.
Read hymn : BABA orun! Emi fe wa