SION yara, k’ o je ise giga re
SION yara, k’ o je ise giga re, So f’ aiye pe Olorun ni mole, Eni to da ‘won orilede ko fe, K’ enikan segbe s’ inu okunkun.
Read hymn : SION yara, k’ o je ise giga re643 hymns
SION yara, k’ o je ise giga re, So f’ aiye pe Olorun ni mole, Eni to da ‘won orilede ko fe, K’ enikan segbe s’ inu okunkun.
Read hymn : SION yara, k’ o je ise giga reSISE tori oru mbo ! Sise li owuro; Sise nigba iri nse, sise n’nu ‘tanna; Sise ki osan to pon, sise nigb’ orun nran, Sise tori oru mbo ! ‘gb ise o pari.
Read hymn : SISE tori oru mbo ! Sise li owuroSISE, akoko nlo, Se tokantokan; Sise, okan nsegbe, Sise, oru mbo,
Read hymn : SISE, akoko nloSO itan kanna fun mi, T’ ohun ni t’ a ko ri; Ti Jesu on ogo Re, Ti Jesu En ‘ ife,
Read hymn : SO itan kanna fun miSUNM’ odo wa, Emmanuel, Wa’ra Israel pada, T’ on sofo li oko eru Titi Jesu y’o tun pada.
Read hymn : SUNM’ odo wa, EmmanuelTAL’ awon wonyi b’ iranwo, Niwaju ‘te Olorun? Gbogbo nwon de ade wura, Egbe ogo wo l’ eyi?
Read hymn : TAL’ awon wonyi b’ iranwo,TAL’ o mo adun isimi, B’ o ye l’ awon t’ o ni, Ti se ‘pin awon ayanfe, Nipa eje Jesu?
Read hymn : TAL’ o mo adun isimiTIRE lailai l’ awa se, Baba Olorun ife; Je k’ a je Tire titi, L’ aiye yi, ati lailai.
Read hymn : TIRE lailai l’ awa seTIRE l’ awa Kristi, Titi aiyeraiye, A fe fi gbogbo okan wa Fun O patapata.
Read hymn : TIRE l’ awa KristiTIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re, O nso ife Re si mi: Sugbon mo fen de l’ apa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O.
Read hymn : TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun ReTIRE l’ ola Baba, O wa n’ ikawo Re; B’ ojum’ ola si mo ba ni, Nipa ase Re ni.
Read hymn : TIRE l’ ola BabaTO nwon, Baba si O, To nwon si O; Awon omo wonyi Ti O fun ni,
Read hymn : TO nwon, Baba si O