OKAN mi, odun kan ninu
OKAN mi, odun kan ninu Aiye re koja lo; Eni ko le gbe ihin pe, Eyi le j’ opin mi.
Read hymn : OKAN mi, odun kan ninuOKAN mi, odun kan ninu Aiye re koja lo; Eni ko le gbe ihin pe, Eyi le j’ opin mi.
Read hymn : OKAN mi, odun kan ninuLASAN ni ero mi nwa ‘pa, T’ o ye fun okan mi kiri; Okan mi ko le n’ isimi, Tor’ aiye ko le bukun mi.
Read hymn : LASAN ni ero mi nwa ‘paJESU b’ oluso, ma sin wa, A nfe, ki Re pupo; F’ onje didara Re bow a, Tun agbo Re se fun wa;
Read hymn : JESU b’ oluso, ma sin waBABA, a f’ ara wa, S’ iso Re l’ ale yi; Da bobo wa, k’ O pa wa mo, Tit’ ile o fi mo.
Read hymn : BABA, a f’ ara waBABA, Omo, on Emi, Eni Metalokan lai, Jo, masai dabobo wa, K’ a le ri ‘mole ola.
Read hymn : BABA, Omo, on EmiONTO mi lo iro ‘bukun, Oro t’ orun tu mi ninu, Ohun ti o wu kemi se Sibe Olorun nto mi lo.
Read hymn : ONTO mi lo iro ‘bukunIGBALA ni, igbala ni, Awa elese nfe; Nitori ninu buburu, T’ a se l’ awa nsegbe.
Read hymn : IGBALA ni, igbala niITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan si, Itan iyanu t’ ife! Ti dun l’eti kikan! Awon Angeli rohin re, awon oluso si gbagbo Elese iwo ki yio gbo? Itan iyanu t’ife.
Read hymn : ITAN iyanu t’ ife! So fun mi lekan siJESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘le O npe loni, o npe loni! Ese t’ o fi ko ife Re sile, T’ o sako jinna rere?
Read hymn : JESU nf’ ohun jeje pe o wa ‘leA KO ni ‘bugbe kan nihin, Onile e roar yanran; B’ o fi gbogb’ aiye ko Garet, Ese mefa ni busun wa.
Read hymn : A KO ni ‘bugbe kan nihinOBIRIN t’ a mu ninu pansaga ‘se On la mu wa fi sun niwaju Jesu; Jesu terire ba. O nkowe n’ ile; T’ agba t’ ewe nf’ obirin yi seleya.
Read hymn : OBIRIN t’ a mu ninu pansaga ‘seOLORUN mi! Olorun mi! Mo f’ ara mi fun O; Dari aisedede ji mi, Ma je ki nsako mo,
Read hymn : OLORUN mi! Olorun mi