KI se l’ ainireti
A! ese mi poju O pon koko; Adale, adale, Ni mo ndese!
Read hymn : KI se l’ ainiretiA! ese mi poju O pon koko; Adale, adale, Ni mo ndese!
Read hymn : KI se l’ ainiretiALEJO kan ma nkankun, Pe E wole O ti npara ‘be tip e Pe E wole.
Read hymn : ALEJO kan ma nkankunETUN won ko fun mi ki ngbo Oro ‘yanu t’ Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro ‘yanu t’ Iye,
Read hymn : ETUN won ko fun mi ki ngboMO fi gbogbo re fun Jesu Patapata laiku kan; Ngo ma fe ngo si gbekele, Ngo si ma ba gbe titi.
Read hymn : MO fi gbogbo re fun JesuOLUWA mi, mo kepe O Ngo ku b’ O ko ran mi lowo; Jo, fi igbala Re fun mi Gbi mi bi mo ti ri.
Read hymn : OLUWA mi, mo kepe OMO Fe mo nipa Jesu sii, F’or’ ofe Re h’ elomiran; Ki nle ri ‘gbala kikun Re, Ki ng mo ‘fe ‘ni to ku fun mi.
Read hymn : MO Fe mo nipa Jesu siiGBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aaye Nn’ orin at’adura, ale; N’ alo at’ ife eba ina, Ibagbe re si wa yi wa ka,
Read hymn : GBAGBO awon ‘ya wa, ‘gbagbo aayeBABA jowo gb’ adura wa, Bi a tin lo loju omi; Iwo ma je ebute wa, Si ma je ile isimi.
Read hymn : BABA jowo gb’ adura waBABA wa Olodumare, ‘Wo t’ o kawo igbi omi, ‘Wo t’ o ti f’ ipo okun fun. Ti ko le ri ibe koja;
Read hymn : BABA wa OlodumareOLORUN so wa n’nu oko Larin omi jinjin, S’ oluso wa bati nwa lo, Ninu ajin oru. 2. Eru ko ye ki o ba wa, Larin iji ti nja, Niwon gba t’ O wa nitsi Larin omi ti nru. 3. Iparoro ati iji, T’ o nkoja lori ‘le, Iwo ni o da gbogbo won, Nwon wa nikawo Re. 4. Nigbat’ awon Aposteli, Wa lori ‘gbi okun, Ase kan lat’ odo Re wa, Mu dake roro wa. 5. Gbati iji to buru ju, Ba nru l’ atokan wa, Oluwa ma sai ba wag be F’ alafia ba wag be. 6. Ninu wahala aiye yi, Ma se amona wa, Titi ao fi de ‘le rere, Nibi t’ ese ko si.
Read hymn : OLORUN so wa n’nu okoAPATA wa n’ ile are, Ojiji Re bo si iyanrin, O npe awon ero ti nkoja, Lati wa si boji l’ aginju.
Read hymn : APATA wa n’ ile areGBATI ‘ji goke l’ ona re, T’ o f’ aniyan kun okan mi, N’ gbekele w’ oke, wipe, “Mo mo p’ Oluwa wa n’ tosi.”
Read hymn : GBATI ‘ji goke l’ ona re