TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re
TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re, O nso ife Re si mi: Sugbon mo fen de l’ apa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O.
Read hymn : TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun ReTIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun Re, O nso ife Re si mi: Sugbon mo fen de l’ apa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O.
Read hymn : TIRE l’ emi se, mo ti gb’ ohun ReTIRE l’ ola Baba, O wa n’ ikawo Re; B’ ojum’ ola si mo ba ni, Nipa ase Re ni.
Read hymn : TIRE l’ ola BabaTO nwon, Baba si O, To nwon si O; Awon omo wonyi Ti O fun ni,
Read hymn : TO nwon, Baba si OTORI Mi at’ ihinrere, E lo so t’ Irapada; Awon onse Re nke “Amin” Tire ni gbogbo ogo;
Read hymn : TORI Mi at’ ihinrereT’ IFE Jesu t’o wa mi, Gbat’ mo nu n’ ese; T’ ore ofe t’ o mu mi Pada bo sin’ agbo;
Read hymn : T’ IFE Jesu t’o wa miT’ OLORUN n’ ijoba gbogbo Oril-ede, e korin ‘yin: E so t’ ipa Re to tobi; Ola Re y’o m’ orin yin dun.
Read hymn : T’ OLORUN n’ ijoba gbogboWA, Emi ‘re, ‘Dada orun Pelu itunu lat’ oke; S’ alabo at’ Oluto wa, To ero at’ isise wa.
Read hymn : WA, Emi ‘re, ‘Dada orunWA, enyin olope, wa, Gbe orin ikore ga; Ire gbogbo ti wole K’ otutu oye to de;
Read hymn : WA, enyin olope, waWA, iwo isun ibukun, Je ki nkorin ore Re: Odo anu ti nsan titi, Bere orin ‘yin kikan;
Read hymn : WA, iwo isun ibukunWA, jek’ a tun pilese ajo wa, K’ a b’ odun yipo, K’ a ma duro tit’ Oluwa yio fi de.
Read hymn : WA, jek’ a tun pilese ajo waWA, Jesu fi ara han; Wa, je k’okan wa mo O: Wa, mu gbogb’ okan gbona, Wa, bukun wa k’a to lo.
Read hymn : WA, Jesu fi ara hanWA, ma sise, Tani gbodo s’ole ninu oko, Gbati gbogbo enia nkore jo? Kaluku ni Baba pase fun pe, –
Read hymn : WA, ma sise