WA, obirin, e ko
WA, obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist, ‘Mole Olorun,
Read hymn : WA, obirin, e koWA, obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist, ‘Mole Olorun,
Read hymn : WA, obirin, e koWA, Oluwa, l’ anu tun wa, Pelu ‘pa ‘p’ okan da, Ongbe ojo np’ oko Sion, Masai ro s’ ori re.
Read hymn : WA, Oluwa, l’ anu tun waWA ba mi gbe! ale fere le tan, Okunkun nsu; Oluwa ba mi gbe, Bi oluranlowo miran ba ye, Iranwo alaini, wa ba mi gbe.
Read hymn : WA ba mi gbe! ale fere le tanWA Emi Mimo, wa, Pelu ipa t’ orun, Si ran ninu anu Re nla Sor’ okan okun wa.
Read hymn : WA Emi Mimo, waWA enyin oloto L’ ayo at’ isegun Wa kalo, wa kalo si Betlehem; Wa kalo wo o!
Read hymn : WA enyin olotoWA k’ a da m’ awon ore wa Ti nwon ti jere na; N’ ife k’ a f’ okan ba won lo S’ ode orun lohun.
Read hymn : WA k’ a da m’ awon ore waWALEJO kan lenu ona: O nkankun je, O ti nkan ri; O ti duro pe, O nduro; Ko s’ ore t’ o je ba lo be.
Read hymn : WALEJO kan lenu onaWA rohin Re yika K’o si korin ogo; Alagbara ni Oluwa Oba gbogbo aiye.
Read hymn : WA rohin Re yikaWA sodo Jesu, mase duro, N’ oro Re l’ O ti f’ ona han wa, O duro li arin wa loni, O nwi jeje pe, “Wa.”
Read hymn : WA sodo Jesu, mase duro“WA sodo Mi, alare Ngo fun nyin n’ isimi.” A! ohun didun Jesu, Ti o p’ elese wa,
Read hymn : WA sodo Mi, alareWA ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu! Wa ‘do Jesu nisin! Nisin wa’ do Jesu!
Read hymn : WA ‘do Jesu!WO! b’ o ti dun to lati ri Awon ara t’ o re; Ara ti okan won s’ okan, L’ egbe ide mimo.
Read hymn : WO! b’ o ti dun to lati ri