ORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po
ORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po, Ife nla ti ko le sa, Bi mo tile s’ aito, S’ife Re yi ni mo ti se;
Read hymn : ORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re poORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re po, Ife nla ti ko le sa, Bi mo tile s’ aito, S’ife Re yi ni mo ti se;
Read hymn : ORE ni Jesu fun mi, tito ‘b’ Ife Re poGBATI ipe Oluwa ba dun T’ akoko ba si pin, T’ imole owuro mimo ntan lailai; Gbat’ awon t’ a ti gbala,
Read hymn : GBATI ipe Oluwa ba dunIJA ti de, ipe sin dun kikankikan, “Wo ‘hamora!” nigbe jake-jado; Oluwa omo-ogun nlo si isegun, Ko pe ti segun Krist’ y’o farahan.
Read hymn : IJA ti de, ipe sin dun kikankikanIMOLE k’ okan mi loni, T’ o logo t’ o si ndan, T’ o tan ju t’ awosanma lo, Jesu n’ imole mi.
Read hymn : IMOLE k’ okan mi loniIWO ha nberu p’ ota yio segun? Okun su lode o sis u ju ninu? Si ferese ati ilekun sile, Jeki ‘ran orun wole.
Read hymn : IWO ha nberu p’ ota yio segunJESU fe k’ emi je ‘mole, Ki ntan lojojumo; Nibi gbogbo kin le wu On, N’ ile, ni skul, l’ode.
Read hymn : JESU fe k’ emi je ‘moleKo ‘s okunkun fun wa t’ o wa t’ o wa ‘nu Jesu, Imole aiye ni Jesu! A nrin n’ imole b’ a ntel’ amona wa, Imole aiye ni Jesu.
Read hymn : GBOGBO aiye ti nu s’ okunkun eseJESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tan, Bi fitila kekere ninu oru; L’ aiye okunkun yi, ka si tan, N’ ipo t’ iwo wa, at’ emi pelu.
Read hymn : JESU nfe k’ a f’ imole ti o pe tanJESU ni gbogb’ aiye fun mi, Iye at’ ayo mi, Agbara mi lojojumo, L’ aisi Re mo subu;
Read hymn : JESU ni gbogb’ aiye fun miKO s’ ore bi Jesu onirele, Ko s’ okan! Ko s’ okan! Ko s’ elomi t’ o le w’ okan wa san, Ko s’ okan! Ko s’ okan!
Read hymn : KO s’ ore bi Jesu onireleLASAN l’ adun aiye npe mi; Mo fe ki njo Jesu, Ohun aiye ko da mi ro; Mo fe ki njo Jesu.
Read hymn : LASAN l’ adun aiye npe miMO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo, On na ko ko ni bi ore aiye sa; Tifetife li on nse ajo lori mi, Mo fe k’ Olugbala mi si je tire.
Read hymn : MO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo