ONIGBAGBO, e bu s’ ayo
ONIGBAGBO, e bu s’ ayo! Ojo nla l’ eyi fun wa; K’ orun f’ ayo korin kikan, K’ igbo at’ odan gberin.
Read hymn : ONIGBAGBO, e bu s’ ayoONIGBAGBO, e bu s’ ayo! Ojo nla l’ eyi fun wa; K’ orun f’ ayo korin kikan, K’ igbo at’ odan gberin.
Read hymn : ONIGBAGBO, e bu s’ ayoWA enyin oloto L’ ayo at’ isegun Wa kalo, wa kalo si Betlehem; Wa kalo wo o!
Read hymn : WA enyin olotoGBO ohun alore, Ji, ara, ji: Jesu ma fere, de, Ji, ara, ji
Read hymn : GBO ohun aloreENYIN Angel’ l’ orun ogo To yi gbogbo aiye ka, E ti ko ‘rin dida aiye, E so t’ ibi Messia,
Read hymn : ENYIN Angel’ l’ orun ogoJI, ‘wo Kristian, k’ o ki oro ayo Ti a bi Olugbala araiye; Dide, k’ o korin ife Olorun, T’ awon Angeli nko n’ ijo kini,
Read hymn : JI, ‘wo Kristian, k’ o ki oro ayoA JIN jin, oru mimo, Okun su, mole de, Awon olus’ agutan nsona, Omo t’o wa l’ oju orun,
Read hymn : A JIN jin, oru mimoSUNM’ odo wa, Emmanuel, Wa’ra Israel pada, T’ on sofo li oko eru Titi Jesu y’o tun pada.
Read hymn : SUNM’ odo wa, EmmanuelA NT’ ona t’ Oluwa war in: A ngb’ agbelebu Re; Gbogb’ egun t’o ngun wa l’ese Ti gun l’ori saju.
Read hymn : A NT’ ona t’ Oluwa war inN’NU ‘se, n’nu ‘ja, Oluwa mi, Ngo rin li ona Re; B’ Iwo ti se l’ emi o se, Nipa iranwo Re.
Read hymn : N’NU ‘se, n’nu ‘ja, Oluwa miJESU, O ha re ‘ra Re le Gbat’ O gb’ ara wa wo? Lati se awotan aisan, Lati l’ arun jade?
Read hymn : JESU, O ha re ‘ra Re leOGABJO gan: l’ oke Olif’ Awon irawo si ti wo; Oganjo gan: nisisyi Jesu nikan ngbadura l’ ogba.
Read hymn : OGABJO gan: l’ oke OlifOPARI! – l’ Olugbala ke, O te ori ba, O si ku; “O pari!” – ire – ije pin, O ti jagun, O si segun.
Read hymn : OPARI! – l’ Olugbala ke