GBO ‘gbe ayo! Oluwa de
GBO ‘gbe ayo! Oluwa de, Jesu t’ a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K’ ohun mura ko ‘ rin
Read hymn : GBO ‘gbe ayo! Oluwa de643 hymns
GBO ‘gbe ayo! Oluwa de, Jesu t’ a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K’ ohun mura ko ‘ rin
Read hymn : GBO ‘gbe ayo! Oluwa deGBO! Orin ti Jubili, O dabi sisan ara; Tabi bi kikun okun, Gbat’ igbi re ba nlu ‘le
Read hymn : GBO! Orin ti JubiliGBO-GB’ ogo iyin ola, Fun O oludande, S’ Eni t’ awon omode Ko Hosanna didun!
Read hymn : GBO-GB’ ogo iyin olaGBOGBO aiye, gbe jesu ga, Angeli’, e wole fun: E mu ade Oba Re wa, Se l’Oba awon oba.
Read hymn : GBOGBO aiye, gbe jesu gaGBOGBO eda dapo, E jo yin Oluwa, E pa ohun nyin po Lati fe oro na;
Read hymn : GBOGBO eda dapoGBOGBO eda labe orun. E fi iyin fun Eleda wa: Ki gbogbo orile-ede Ko Olugbala wa l’ orin.
Read hymn : GBOGBO eda labe orunGBOGBO eje eran, Ti pepe awon ju, Ko le f’ okan l’ Alafia, Ko le we eri nu.
Read hymn : GBOGBO eje eranGBOGB’ ogun orun nro keke, Angeli mu harpu won, Awon mimo nt’ ohun won se Lati josin t’ o l’ ogo;
Read hymn : GBOGB’ ogun orun nro kekeGB’ adura wa Oluwa, F’ awon omo t’ O fun wa, Pin wa ninu ‘bukun Re, Si fun won l’ ayo l’ orun.
Read hymn : GB’ adura wa OluwaGB’ ohun to t’ orun wa ti wi, Bukun f’ oku onigbagbo Nwon bo ninu lala aiye Aiye ki yio tun mo won mo,
Read hymn : GB’ ohun to t’ orun wa ti wiGB’ ohun t’ o orun wa ti wi F’ awon mimo t’ o ku, “Didun l’ orun oruko won, ‘Busun won n’ itura.”
Read hymn : GB’ ohun t’ o orun wa ti wiGB’ ope mi, Oluwa, Lat’ okan l’ o ti wa, Iwo t’ O gba die opo, K’yo kegan ‘more mi.
Read hymn : GB’ ope mi, OluwaGB’ opo duru pelu ohun Nwon nkorin iyin loke; Jesu joba, orun si yo; Olorun ife joba;
Read hymn : GB’ opo duru pelu ohunGB’ ori soke alare, Tori ayo nbo l’ owuro, Olorun so n’nu oro Re Pe ayo ma nbo l’ owuro,
Read hymn : GB’ ori soke alareHA! egbe mi, e w’ asia Bi ti nfe lele Ogun Jesu fee de na, A fere segun!
Read hymn : HA! egbe mi, e w’ asiaHALLELUYAH, Halleluyah, E gbe ohun ayo ga, E korin inudidun, K’ e si yin olorun wa,
Read hymn : HALLELUYAH, HalleluyahIBU ife! O le je Pe a p’anu mo fun mi; Olorun mi ha le da ‘Binu ro fun elese?
Read hymn : IBU ife! O le jeIBUKUN ni f’ oku, T’ o simi le Jesu; Awon t’ o gb’ ori won Le okan aiya Re.
Read hymn : IBUKUN ni f’ okuIFE lo to bayi? Ohun gbogbo pari, O ti pari gbogbo ise T’ O tori re w’ aiye.
Read hymn : IFE lo to bayiIFE l’ Olorun: anu Re Mole s’ ona wa gbogbo; O ns’ ayo ji, O ndin ‘se ku: Ogbon nla ni olorun.
Read hymn : IFE l’ Olorun: anu ReIFE mi s’ ibi ti wa pe, Lai beru itiju, Titi mo fi r’ ohun titun, Ti o da mi duro.
Read hymn : IFE mi s’ ibi ti wa peIFE orun alailegbe, Ayo orun sokale: Fi okan wa se ‘bugbe Re, Se asetan anu Re;
Read hymn : IFE orun alailegbeIFE orun t’ o teriba Lati pin ninu ekun wa: Iwo l’ a k’ aniyan wa le, Ko si nkan gbat’ O sunmo wa.
Read hymn : IFE orun t’ o teribaIFE orun! alailegbe! N’nu ase mimo yi, Ogo re kun, ‘mole re po, Ti ntan iye jade.
Read hymn : IFE orun! alailegbe