OLUWA ni Oba
OLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi;
Read hymn : OLUWA ni Oba643 hymns
OLUWA ni Oba; E bo Oluwa nyin; Eni kiku, s’ ope, Y’ ayo’ segun titi;
Read hymn : OLUWA ni ObaOLUWA orun at’ aiye! Jesu, Omo ninu ara! Emi Mimo fun ‘toju wa! E gbo, ki E si gb’ eje wa.
Read hymn : OLUWA orun at’ aiyeOLUWA po! Ogun orun wole fun, Ati enyin t’ o nrin l’ aiye. E yon in orin mimo niwaju Re, Ki e si yin Eleda yin.
Read hymn : OLUWA po! Ogun orun wole funOLUWA sokale, Bukun awon ‘mo ma, Laipe, ki ife won le te Si ore-ofe Re.
Read hymn : OLUWA sokaleOLUWA t’ o mo julo, K’ a wole l’ oruko Re; Ife Re ki ye titi, Kab’yesi Oba rere.
Read hymn : OLUWA t’ o mo juloOLUWA wa mimo, Ti ogun orun nyin, Masai gbo wa; Kerubu, Serafu,
Read hymn : OLUWA wa mimoOLUWA wa, a nkorin ti Owo nla t’ o mu wa duro; Odun titun f’ anu Re han, Jek’ anu pelu re d’ opin.
Read hymn : OLUWA wa, a nkorin tiOLUWA wow a l’ ese Re Otosi elese; Gege bi eniti nbebe, A wa ni ase Re.
Read hymn : OLUWA wow a l’ ese ReOLUWA, a wa ‘do, Re, L’ese Re l’ a kunle si; A! ma kegan ebe wa, A o wa O lasan bi?
Read hymn : OLUWA, a wa ‘do, Re,OLUWA, alaimo l’ emi, Ninu ese l’ a gbe bi mi, Eniti mo se lara re L’ o fi ese ba aiye je.
Read hymn : OLUWA, alaimo l’ emiOLUWA, Baba orun, B’ oju woo mo-‘do Re Ti nro t’ igbe aiye re, Ati ipo re si O.
Read hymn : OLUWA, Baba orunOLUWA, bawo l’ okan mi Ti bale lekan ri; Mo wa laye laisi ofin, Mo seb’ ese mi ku.
Read hymn : OLUWA, bawo l’ okan mi