Yoruba Baptist Hymns
OLUWA, bawo l’ okan mi
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
OLUWA, bawo l’ okan mi
Ti bale lekan ri;
Mo wa laye laisi ofin,
Mo seb’ ese mi ku.
Verse 2
Ireti duro sinsin,
Sugbon nigb’ ofin de,
Pelu imole t’ o n’ ipa,
Mo ri alaiye mi.
Verse 3
Ebi mi ko han tobi ri,
Ki nto f’ iberu ri,
Bi ofin Re ti to, t’ o pe,
T’ o si je mimo to.
Verse 4
‘Gbana l’eru pa okan mi,
Ese mi tun soji,
Mo ti bi Olorun ninu,
Ireti mi si ku.
Verse 5
Olorun, mo nke lais’ are
Fun ipa igbala;
Ja ajaga ese kuro,
K’ O da eru n’ ide.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/oluwa-bawo-l-okan-mi/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.