OLUWA, Baba orun
First time here? Explore the hymn tools.
Verse 1
OLUWA, Baba orun,
B’ oju woo mo-‘do Re
Ti nro t’ igbe aiye re,
Ati ipo re si O.
Verse 2
Mo n’ igbgbo si Jesu,
Si agbara iku Re,
S’ ajinde Re, apere
Iye lehin iku mi.
Verse 3
Emi Re l’ o s’ ise yi,
L’ O mu mi mo ebi mi,
L’ O toka ‘gbala si mi,
L’ O mu mi gba Kristi gbo.
Verse 4
Sugbon sibe okan mi,
Nd’igba se kilakilo,
Nitor’ese to mo nda,
Alailera sa l’emi.
Verse 5
Fun mi ni idaloju
Isimi okan toto,
T’awon ‘mo-ehin Re gbo,
Ti aiya won si bale.
Verse 6
Wi f’okan mi, Oluwa,
(Iwo nikan l’O le wi,)
Pe a ti k’oruko re
Sinu ‘we iye l’oke.
Verse 7
‘Gbana mo le n’igboya
Lati wi bi paulu pe,
“Ko s’ohun l’aiye, l’orun
T’o le ya t’emi Tire.”
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.