Yoruba Baptist Hymns
WO, awon t’ o ‘so ala
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
WO, awon t’ o ‘so ala,
Nwon duro leti odo,
Nwon k’ ehin s’ aiye at’ esu,
Nwon ntele Atebomi;
Nwon si nreti,
Lati se ase Jesu.
Verse 2
Wo bi nwon ti duro l’ eru,
Sugbon pelu ireti,
Nwon mo pe Olugbala won
L’ O pase odo lilo,
Jordan’ tutu,
Sugbon igbagbo gbona.
Verse 3
Si wo awon arakunrin –
Egbon nwon ninu Jesu,
Wo bi awon tin a ‘wo ife
Nwon sa ti dabi nwon ri,
Nisisiyi,
Nwon ny’ ayo idariji.
Verse 4
Lo, tele Olugbala nyin;
E f’ oju igbagbo ri;
A! orun si, Emi Baba
Si nke lat’ oke wipe,
“Awon nwonyi
Ni ayanfe omo Mi.”
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/wo-awon-t-o-so-ala/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.