Yoruba Baptist Hymns
LI o wuro Iwo o gbo
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
LI o wuro Iwo o gbo
Ohun mi, Oluwa;
S’ odo Re l’ emi o dari
Oju adura mi.
Verse 2
Si oke ti Jesu lo be
Fun awon enia Re;
Ti o fi irahun wa han
Baba Re l’ ori ‘te.
Verse 3
Oba niwa ju Eniti
Elese ko le gbe;
O ko l’ ayo si elese,
Ko le gb’ owo ‘tun Re.
Verse 4
Sugbon emi y’o wa ‘le Re
Lati to anu wo,
Emi k’y’o si ye lati sin
Ninu agbala Re.
Verse 5
Emi Re iba le ma to
Ese mi sir ere.
Ko mu ona ise mi han
Gbangba niwaju Re.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/li-o-wuro-iwo-o-gbo/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.