A BAPTIS’ wa sinu iku
A BAPTIS’ wa sinu iku, Nipa itebo ‘mi; A sin wa ‘nu ‘boji Jesu, A sin wa pelu Re. A ba Krist’ ku k’ a ba ye se, K’ a le ji pelu Re, K’ a le
Read hymn : A BAPTIS’ wa sinu iku643 hymns
A BAPTIS’ wa sinu iku, Nipa itebo ‘mi; A sin wa ‘nu ‘boji Jesu, A sin wa pelu Re. A ba Krist’ ku k’ a ba ye se, K’ a le ji pelu Re, K’ a le
Read hymn : A BAPTIS’ wa sinu ikuA F’ iyin aiku fun ‘Fe Olorun Baba, Fun itunu t’ aiye, At’ ireti t’ orun: O ran ‘Mo Re aiyeraiye Lati ku fun ese t’ a da. T’ Olorun Omo ni
Read hymn : A F’ iyin aiku funA F’ ope f’ Olorun L’ okan ati ohun wa, Eni s’ ohun ‘yanu, Ninu Enit’ araiye nyo; Gbat’ a wa l’ omowo On na l’ o ntoju wa, O si nf’ ebun ife
Read hymn : A F’ ope f’ OlorunA IGBAGBO bila! T’ emi l’ Oluwa On o si dide fun igbala mi; Ki nsa ma gbagura, On o se ‘ranwo; ‘Gba Krist’ wa lodo mi, ifoiya ko si. B’ ona
Read hymn : A IGBAGBO bila! T’ emi l’ OluwaA JESU, Iwo nduro Lode, lehin ‘lekun, Iwo fi suru duro Lati koja s’ ile; ‘Tiju ni fun wa, Kristian’, Awa ti nj’ oko Re! Itiju gidigidi! B’ a
Read hymn : A JESU, Iwo nduroA JIN jin, oru mimo, Okun su, mole de, Awon olus’ agutan nsona, Omo t’o wa l’ oju orun, Simi n’nu alafia Simi n’nu Alafia. Ajin jin, oru mi
Read hymn : A JIN jin, oru mimoA KO ni ‘bugbe kan nihin, Onile e roar yanran; B’ o fi gbogb’ aiye ko Garet, Ese mefa ni busun wa. A ko ni ‘bugbe kan nihin, Or’ aiye fowob
Read hymn : A KO ni ‘bugbe kan nihinA NT’ ona t’ Oluwa war in: A ngb’ agbelebu Re; Gbogb’ egun t’o ngun wa l’ese Ti gun l’ori saju. Opo ‘gba l’ oju wa l’ ayo, L’ o kun fun omi
Read hymn : A NT’ ona t’ Oluwa war inA RA, e wa ba mi s’ ofo, E wa sodo Olugbala; Wa, e je k’ a jumo s’ ofo; A kan Jesu m’ agbelebu. ko ha s’ omije loju wa bi awon Ju ti nfi se
Read hymn : A RA, e wa ba mi s’ ofoA RE mu o okan re poruru? So o fun Jesu, so o fun Jesu; Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu nikan. So o fun Jesu; so o fun Jesu, On l’ore
Read hymn : A RE mu o okan re poruruA WON eye n’ ife, Kolokolo n’ iho, enia n’ ile: Eda n’ ib’ isimi Sugbon Jesu ko r’ ibi gborile. Sibe O mu sinmi Wa f’ awon elese on alare;
Read hymn : A WON eye n’ ife“A YE si mbe!” ile Odagutan, Ewa ogo re npe o pe, “Ma bo”, Wole, wole, wole nisisiyi. Ojo lo tan, orun si fere wo, Okunkun de tan, ‘mole nk
Read hymn : A YE si mbe!” ile OdagutanA YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe Re, Fun Jesu ti o ku to si lo soke Halleluya, tire logo Halleluya, Amin; Halleluya, tire logo, Tun mu soji.
Read hymn : A YIN O ‘lorun, nitor’ Omo ‘fe ReA! mba le l’ egberun ahon. Fun ‘yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re. Jesu t’ O s’ eru wa d’ ayo, T’ O mu ‘banuje tan; Orin ni l’
Read hymn : A! mba le l’ egberun ahonA! RO ti ibugbe orun, Li eba odo imole, Nibit’ awon mimo wa l’ aiku, T’ a wo won li aso funfun. Lok’ orun! Lok’ orun! A! ro ti ibugbe orun!
Read hymn : A! RO ti ibugbe orunA, JEKI oro mimo Re Fi agbara si okan mi, F’ imole at’ ife orun Wi f’ okan mi pe, “Wo t’ emi.” Oro Re t’ o kun fun ayo, Yio le eru mi s’ ap
Read hymn : A, JEKI oro mimo ReA, JESU Alabukun, A m’ orin ayo wa, Ohun at’ okan ‘pe wa L’ ayo l’ a gbe si O; O ga, O si mo julo Larin Angel’ l’ oke, Sibe ninu ‘rele wa If
Read hymn : A, JESU AlabukunABA le n’ igbagbo aye, B’ o ti wu k’ ota po; Igbagbo ti ko je mira Fun aini at’ os Igbagbo ti ko je rahun, Labe ibawi Re; Sugbon ti nsimi l
Read hymn : ABA le n’ igbagbo aye“ABBA, Baba,” a sunmo O L’ oruko Jesu owon; Aw’ omo Re t’ o pe nihin, Nfe ‘bukun t’ O se ‘leri; Eje Re we wa n’n ese wa, Nipa Re l’ a sunmo
Read hymn : ABBA, Baba,” a sunmo OABE, a fe ri o, Ojo ‘simi rere, Gbogbo ose a ma wipe, Iwo o ti pe to? O ko w ape Kristi Jinde ninu oku; Gbogbo ose a ma wipe, Iwo o ti pe t
Read hymn : ABE, a fe ri oADUA didun adua didun, T’o gbe mi lo kuro l’aiye, Lo ‘waju ite Baba mi, Ki nso gbogbo edun mi fun; Nigba ‘banuje at ‘aro Adua l’abo fun okan
Read hymn : ADUA didun adua didunAFRIK’ ‘le wara at’ oyin, Ni orile aiye now si, T’ Olorun fun ania dudu, Fun ini re titi lailai. Ote owo-eru ‘gbani, Ko f’ okan baba wa bal
Read hymn : AFRIK’ ‘le wara at’ oyinAFUN iho ayo mimu S’ Olorun Oba nla! K’ile gbogbo lo ahon won K’o si korin ‘segun. Jesu Oluwa goke Eso orun yi ka, Nwon ba goke bi O ti nlo
Read hymn : AFUN iho ayo mimuAGBELEBU ni ere mi, Nibe ni a rubo fun mi; Nibe l’ a kan Oluwa mo Nibe l’ Olugbala mi ku. Kini o le fa okan Re Lati te ‘ri gba iya mi? Aim
Read hymn : AGBELEBU ni ere mi