YBH 648

MO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo

1. MO n’ Olugbala t’ o mbere nin’ ogo,
On na ko ko ni bi ore aiye sa;
Tifetife li on nse ajo lori mi,
Mo fe k’ Olugbala mi si je tire.

Refrain
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Mo ngbadura fun o.

2. Mo ni Baba; t’ o fun mi ni ileri
Ireti ainipekun t’ o ni ‘bukun;
On y’o si pe mi lati pade Re l’ orun,
A, on ‘ba je k’ emi mu o wa pelu!

Refrain
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Mo ngbadura fun o.

3. Mo n’ agbada t’ o mo ninu ewa re,
Nduro nin’ ogo fun ‘yanu mi l’ oke
Nigba’ a fifun mi t’ o ndan n’ imole re
Mo fe k’ iwo na ri okan gba pelu!

Refrain
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Mo ngbadura fun o.

4. Gba Jesu ti ri o, ro ‘tan na kale
P’ Olugbala mi si je tire pelu;
Si ma gbadura kin won le wo nu ogo
Adura re y’o gba o ti gba fun o!

Refrain
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Fun o mo ngbadura,
Mo ngbadura fun o.

(Visited 439 times, 1 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you