1. MO ti ni Jesu l’ore,
O j’ ohun gbogbo fun mi,
On nikan l’arewa ti okan mi fe,
On n’itanna ipado;
On ni enikan na
T’o le we mi nu kuro nin’ese mi;
Olutunu mi l’ O je,
N’nu gbogbo wahala,
On ni ki nk’aniyan mi l’On lori
On n’Itanna Ipado
Irawo Owuro
On nikan l’arewa ti okan mi fe.
Olutunu mi l’ O je,
N’nu gbogbo wahala,
On ni ki nk’aniyan mi l’On lori
On n’Itanna Ipado
Irawo Owuro
On nikan l’arewa ti okan mi fe.
2. O gbe gbogbo ‘banuje,
At’irora mi ru;
O j’Odi agbara mi n’gba danwo;
‘T Re mo k’ohun gbogbo,
Ti mo ti fe sile,
O si f’agbara Re gbe okan mi ro,
Bi aiye tile ko mi
Ti Satan dan mi wo,
Jesu yio mu d’ opin irin mi:
On n’ itanna ipado,
Irawo Owuro
On nikan l’ Arewa ti okan mi fe,
3. On ki y’o fi mi sile
Be k’yo ko mi nihin,
N’ iwon ti mba f’ igbagbo p’ ofin Re mo
O j’ odi ina yi mi ka,
Ng’ ki y’o beru-keru,
Y’o fi manna Re b’ okan mi t’ ebi npa;
Gba mba d’ ade n’ ikehin,
Ngo r’ oju ‘bukun Re
Ti adun Re y’o ma san titi lai,
On n’ Itanna Ipado
Irawo Owuro
On nikan l’ Arewa ti okan mi fe,