YBH 354

HA! egbe mi, e w’ asia

1. HA! egbe mi, e w’ asia
Bi ti nfe lele
Ogun Jesu fee de na,
A fere segun!
“D’ odi mu, emi fere de,”
Beni Jesu nwi,
Ran ‘dahun pada s’ orun pe,
Awa o di mu.

2. Wo opo ogun ti mbowa,
Esu nko nwon bo,
Awon alagbara nsubu,
A fe damu tan.

3. Wo asia Jesu ti nfe,
Gbo ohun ipe;
A o segun gbogbo ota,
Ni oruko Re,

Stanza 4 of Hymn 354

Ogun gbona girigiri,
Iranwo w ambo;
Balogun w ambo wa tete,
Egbe, tujuka.

(Visited 25,419 times, 10 visits today)

Sign up for our Newsletter

We promise not to spam you