Yoruba Baptist Hymns
B’ENU mi dun bi t’ awon ju
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
B’ENU mi dun bi t’ awon ju,
T’ ede mi ta t’ angeli yo;
Laisi ife mo dab’ ide,
Ti ohun re nhan ni l’ eti.
Verse 2
Bi mo le f’ ogbon mi wasu
Gbogbo nkan tin won nse l’ orun;
B’ igbagbo mi le s’ oke n’di,
Lais ife, asan ni mo je.
Verse 3
Bi mo pin gbogbo ii mi,
Lati fi b’ awon alaini,
Ti mo f’ ara mi fun sisun,
Lati gb’ ogo awon martir’:
Verse 4
Bi nko f’ eda at’ Olorun,
Gbogbo ‘reti mi je lasan,
Gbogbo ebun t’ o wu k’ a ni,
Ko s’ eyit’ o dabi ife.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/benu-mi-dun-bi-t-awon-ju/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.