EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de
First time here? Explore the hymn tools.
Verse 1
EMI ko mo ‘gbat’ Oluwa yio de,
Lati mu mi lo si ile Re orun,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Refrain
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Verse 2
Emi ko mo orin t’ angeli nko,
Emi ko si mo iro duru won,
Sugbon mo mo pea o d’ oruko Jesu,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Refrain
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Verse 3
Emi ko mo b’ ile m’ orun ti ri,
Ati oruko tin go je nibe,
Sugbon mo mo pe Jesu yio pe mi wo ‘le,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Refrain
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Sugbon mo mo pe wiwa Re yio je ‘mole,
Eyini yio j’ ogo fun mi,
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.