Yoruba Baptist Hymns
MA wo ‘le, Jesu t’ a nreti
First time here? Explore the hymn tools.
Selected words
Verse 1
MA wo ‘le, Jesu t’ a nreti,
T’a bi lati gba ni la!
Gba wa low’ ese at’ eru,
K’ a r’ isimi ninu Re.
Verse 2
Ipa at’ itunu Israel;
Ireti awon mimo;
Olufe gbogbo orile,
Ayo okan ti nreti.
Verse 3
A bi O lati gb’ eda la,
Enia – sugbon Olorun –
Lati job alai ninu wa,
Mu ‘joba rere Re wa.
Verse 4
Nipa Emi Re t’ o wa lai,
Nikan joba ninu wa;
Nipa ‘toye Re t’ o po to,
Gbe wa s’ ite ogo Re.
From Yoruba Baptist Hymnshttps://yorubabaptisthymns.com/hymn/ma-wo-le-jesu-t-a-nreti/
Conversation 0 comments
Share a reflection or ask a question. Comments are reviewed before they appear.
Report a lyric correction
Include the verse and a hymnbook or source reference. Submissions are reviewed before any lyrics change.
Share anonymously
No account is required. Anonymous comments include the city and country you choose to share.